Sérbíà
Sérbíà (pipe: /ˈsɜrbiə/ (ìrànwọ́·info)), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Serbia (Àdàkọ:Lang-sr), je orile-ede alafileyika to budo si oritameta Arin- ati Apaguusuilaorun Europe, to gbale apaguusu Pannonian Plain ati apa arin Balkani. Serbia ni bode pelu orile-ede 8, Hungary ni ariwa; Romania, Bulgaria ni ilaorun; orile-ede Makedonia ni guusu; ati Kroatia, Bosnia ati Herzegovina, Montenegro ni iwoorun; bode re pelu Albania je jijiyansi. Botileje alafileyika, orile-ede yi jamo Okun Dudu lati inu Odo Danubi. Oluilu re, Belgrade, je ikan ninu awon titobijulo ni Apaguusuilaorun Europe.
Republic of Serbia Република Србија Republika Srbija | |
---|---|
Motto: [Tantum Iunctum Mos Servo Nos] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Only Unity Will Save Us) | |
Orin ìyìn: Боже правде / Bože pravde "God of Justice" | |
![]() Ibùdó ilẹ̀ Sérbíà (orange) on the European continent (white) — [Legend] | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Belgrade |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Serbian |
Lílò regional languages | Hungarian, Slovak, Romanian, Croatian, Rusyn 1 Albanian 2 |
Orúkọ aráàlú | ara Serbia |
Ìjọba | olominira onilesofin |
Slavica Đukić Dejanović | |
Mirko Cvetković | |
Tomislav Nikolić | |
Aṣòfin | Ileigbimo Asofin |
Establishment | |
7th century | |
1217 | |
1345 | |
• Independence lost 4 | 1459 |
• First Serbian Uprising5(Modern Statehood) | February 15, 1804 |
25 March 1867 | |
13 July 1878 | |
25 November 1918 | |
Ìtóbi | |
• Total | [convert: invalid number] (113th) |
• Omi (%) | 0.13 |
Alábùgbé | |
• 2007 estimate | 10,147,398 |
• 2002 census | 7,498,0016 |
• Ìdìmọ́ra | 115/km2 (297.8/sq mi) (94th) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $81.982 billion (IMF) |
• Per capita | $10 985 |
Gini (2007) | .24 low |
Owóníná | Serbian dinar7 (RSD) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Àmì tẹlifóònù | 381 |
ISO 3166 code | RS |
Internet TLD | .rs (.yu)8 |
1 All spoken in Vojvodina. 2 Spoken in Kosovo. 3 Raška, preceded by Kingdom of Duklja (1077) 4To the Ottoman Empire and Kingdom of Hungary 5The Proclamation (of independence, 1809) 6 excluding Kosovo 7 The Euro is used in Kosovo alongside the Dinar. 8 .rs became active in September 2007. Suffix .yu will exist until September 2009. |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |