Àwọn èdè Sílàfù

(Àtúnjúwe láti Slavic languages)

Àwọn èdè Sílàfù (bakanna bi Àwọn èdè sílàfónì), je egbe awon a group of closely related èdè ti won ni ibatan mo ara won ti àwon eniyan Silafu unso, o si wa labe egbe àwon ede India-Europe, o ni awon esoede kakiri ni Apailaorun Europe, kakiri ni Balkani, awon apa Arin Gbongan Europe, ati apaariwa Asia.

èdè Sílàfù
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
Kakiri Central and Eastern Europe ati Russia
Ìyàsọ́tọ̀:Indo-European
Èdè àkọ́kọ́sọ:Proto-Slavic
Àwọn ìpín-abẹ́:
ISO 639-2 and 639-5:sla

  Countries where an East Slavic language is the national language
  Countries where a West Slavic language is the national language
  Countries where a South Slavic language is the national language