Timo Werner (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈtiːmoː ˈvɛɐ̯nɐ];[4][5] tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1996, ( 6th March 1996) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Germany tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù-jẹun lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì fún ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá Chelsea.

Timo Werner
20180602 FIFA Friendly Match Austria vs. Germany Timo Werner 850 0621.jpg
Werner with Germany in 2018
Personal information
OrúkọTimo Werner[1]
Ọjọ́ ìbí6 Oṣù Kẹta 1996 (1996-03-06) (ọmọ ọdún 26)[2]
Ibi ọjọ́ibíStuttgart, Germany
Ìga1.80 m[3]
Playing positionForward
Club information
Current clubIkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá Chelsea
Number11
Youth career
0000–2002TSV Steinhaldenfeld
2002–2013Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá VfB Stuttgart
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ọdún 2013 sí 2016Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá VfB Stuttgart95(13)
ọdún 2014Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá VfB Stuttgart II1(1)
ọdún 2016 sí 2020Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá RB Leipzig127(78)
2020–Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá Chelsea32(6)
National team
2010–2011Orílẹ̀-èdè Germany U154(3)
2011–2012Germany U165(2)
2012–2013Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ orílẹ̀ èdè tí kò ju ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún lọGermany U1718(16)
2013–2015Germany U1914(10)
2015–2016Germany U217(3)
2017–Germany38(15)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19:14, 1 May 2021 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 20:42, 31 March 2021 (UTC)

Werner bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá jẹun gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n fún ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù VFB Stuttgart lọ́dún 2013, òun sìn ni ọ̀dọ́mọdé tó kéré jù lọ láti kọ́kọ́ bá àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù náà díje gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n. Nígbà tí ó di ọdún 2016, Werner dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù RB Leipzig lọ́mọ ogún ọdún, òun sìn ní ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá yìí kọ́kọ́ rà tí owó rẹ̀ wọ́n tó €10 million, owó ìlú òyìnbó. Bẹ́ẹ̀ náà, òun ni ọmọdé àkọ́kọ́ tí ó kópa nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ 159 àti 200 nínú ìdíje bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá àgbábuta tí orílẹ̀ èdè Germany. Bákan náà, Werner ni agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n kejì tó gbá bọ́ọ̀lù sáwọ̀n jùlọ nínú ìdíje àgbábuta tí orílẹ̀ èdè Germany lọ́dún 2019 sí 2020, kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá Chelsea.

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "FIFA World Cup Russia 2018: List of Players: Germany" (PDF). FIFA. 15 July 2018. p. 12. Archived from the original (PDF) on 11 June 2019. 
  2. "Timo Werner: Overview". ESPN. Retrieved 25 June 2020. 
  3. "Timo Werner". Chelsea F.C. Retrieved 15 August 2020. 
  4. "Duden | Timo | Rechtschreibung, Bedeutung, Definition" (in Èdè Jámánì). Duden. Retrieved 28 July 2018. Timo 
  5. "Duden | Werner | Rechtschreibung, Bedeutung, Definition" (in Èdè Jámánì). Duden. Retrieved 28 July 2018. Wẹrner