Venus Ebony Starr Williams[1] (ojoibi 17 Osu Kefa, 1980) je ara Amerika agba tenis alagbase to wa ni ipo karun lagbaye fun awon adije enikan ati ipo kinni lagbaye fu awon adije enimeji. O ti wa ni ipo kinni lagbaye fun awon adije enikan latowo WTA ni emeta otooto. O bo si ipo akoko lagbaye ni igba akoko ni ojo 25 Osu Keji, 2002. Venus ni egbon Serena Williams to un na je agba tenis.

Venus Williams
Venus Williams at the 2010 US Open 01.jpg
Orílẹ̀-èdè USA USA
Ibùgbé Palm Beach Gardens, Florida
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹfà 17, 1980 (1980-06-17) (ọmọ ọdún 39)
Lynwood, California, U.S.
Ìga 1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà October 31, 1994
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó $ 28,460,747
(2nd in overall earnings)
Iye ìdíje 617–156 (80.3%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 45 (Tied for 7th in overall rankings)
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (February 25, 2002)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 41 (October 8, 2012)
Open Austrálíà F (2003)
Open Fránsì F (2002)
Wimbledon W (2000, 2001, 2005, 2007, 2008)
Open Amẹ́ríkà W (2000, 2001)
Ìdíje WTA W (2008)
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal.svg Gold medal (2000)
Iye ìdíje 163–24
Iye ife-ẹ̀yẹ 20
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (June 7, 2010)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 34 (October 8, 2012)
Open Austrálíà W (2001, 2003, 2009, 2010)
Open Fránsì W (1999, 2010)
Wimbledon W (2000, 2002, 2008, 2009, 2012)
Open Amẹ́ríkà W (1999, 2009)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal.svg Gold medal (2000, 2008, 2012)
Iye ìdíje 25–6 (80.6%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 2
Open Austrálíà W (1998)
Open Fránsì W (1998)
Wimbledon F (2006)
Open Amẹ́ríkà QF (1998)
Last updated on: October 8, 2012.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Women's tennis
Adíje fún the Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan USA
Wúrà 2000 Sydney Singles
Wúrà 2000 Sydney Doubles
Wúrà 2008 Beijing Doubles
Wúrà 2012 London Doubles


ItokasiÀtúnṣe