Àṣà jẹ́ àpapọ́ ìgbé-ayé tí ó jẹ́ àdámọ́ tí a mọ̀ mọ́ ẹ̀yà kan. Èyí túmọ̀ sí ìhùwàsí, ìṣe, ìgbàgbọ́ wọn tí wọ́n fi yàtọ̀ sí àwọn ẹ̀yà mìíràn.[1]


Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe