Àròfọ̀ Lórí Eyín

(Àtúnjúwe láti ÀRÒFỌ̀ LÓRÍ ẸYIN)

Eyín jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀ya ara tí a máa ń lo láti jẹ oúnjẹ, gé nǹkan, já nǹkan àti láti fi run nǹkan nínú ẹnu wa.

Àròfọ̀ ẹyín

àtúnṣe

Ẹyin dára fún àmúlò ẹ̀dá

Bí adìẹ ṣe ń yẹ́yin

Bẹ́ẹ̀ náà ni pẹ́pẹ̀yẹ ń yé tirẹ̀

Yàtọ̀ sí àwọn ohun abìyẹ́

Ejò àti aláǹgbá náà máa ń yẹ́yin

Ẹyin dùn láti jẹ, pàápàá

Ẹyin adìẹ lórí búrẹ́dì àti iṣu.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe