Àanu Ayègbusi jẹ elere tennisi lobinrin ni orilẹ ede Naigiriya ti a bini 30, óṣu November ni ọdun 1993. Arabinrin na jade ni ile iwe giga ti ilu Port Harcourt[1].

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Àànu Ayegbusi ni wọn dibo fun gẹgẹbi elere tennis lobinrin to pegede julọ ni ọdun 2017[2].
  • Àànu kopa ninu ere Idije Open tennis Eko to waye ni Eko ni ọdun 2019 pẹlu awọn elere iyoku to wa lati oriṣirì ilu lati ókè ókun[3].
  • Ni ọdun 2021, Aanu kopa ninu Ere idije ti Open CBN Tennis ni ilu Abuja[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://m.aiscore.com/tennis/player-anu-ayegbusi/07d0odu10rgf9qn
  2. https://nigeriatennislive.com/anu-ayegbusi-voted-nigerias-best-female-player-in-2017-see-how-people-voted/
  3. https://www.premiumtimesng.com/sports/354283-tennis-240-players-enter-for-2019-lagos-open-championships.html
  4. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-23. Retrieved 2022-05-23.