Àbí Ọlájùwọ́n
Personal information | |
---|---|
Born | 6 Oṣù Keje 1988 Houston, Texas |
Nationality | Ọmọ Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà |
Listed height | 6 ft 4 in (1.93 m) |
Listed weight | 236 lb (107 kg) |
Career information | |
High school | Marlborough School (Los Angeles, California) |
College | Oklahoma (2006–2010) |
NBA draft | 2010 / Round: 3 / Pick: 28k overall |
Selected by the Chicago Sky | |
Pro playing career | 2010–2013 |
Position | Center |
Number | 21, 34 |
Coaching career | 2014–present |
Career history | |
As player: | |
Àdàkọ:Wnbay | Chicago Sky |
2010 | SEAT-Lami-Véd Győr |
2011 | CSM Satu Mare |
Àdàkọ:Wnbay | Tulsa Shock |
2011–2012 | Hapoel Rishon LeZion |
2012 | ŽKK Novi Zagreb |
2012 | BC Castors Braine |
2012 | Esportivo Ourinhos |
2012 | Heilongjiang Chenneng |
2013 | Caja Rural Zamarat |
As coach: | |
2014–2016 | Cal State Fullerton (assistant) |
2016–2018 | Eastern Michigan (assistant) |
Àbí Ọlájùwọ́n tí apèjá orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Alon Abísọ́lá Arisicate Àjọkẹ́ Ọlájùwọ́n, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1988 jẹ́ akọ́ni àti agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà. Ó jẹ́ Ọmọbìnrin gbajúmọ̀ agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n, Hakeem Olajuwon. Gẹ́gẹ́ bí ìtumọ̀ orúkọ rẹ̀, Abísọ́là Ọlájùwọ́n, ó jẹ́ ọmọ atàpáta-dìde, ọmọ tí wọ́n bí sínú ọlá, tí ọlá náà ju àwọn ju àwọn ọ̀tá lọ̀.[1]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n
àtúnṣeNí ilé ẹ̀kọ́ gíga àti kọ́lẹ́ẹ̀jì
àtúnṣeWọ́n bí Ọlájùwọ́n sí Houston, ní Ìpínlẹ̀ Texas lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó wà nínú ìkọ̀ tí wọ́n ń gbá bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n fún ilé-ìwé gíga California àti ní, ó sìn rànwọ́nlọ́wọ́ láti gba àmìn-ẹ̀yẹ mẹ́ta léraléra nínú ìdíje apá iwọ̀-oòrùn Amẹ́ríkà. Ọlájùwọ́n gbàmìn-ẹ̀yẹ ti McDonald's All-American lọ́dún 2006,[1] Ó tún wà lára àwọn tí wọ́n gbà àmìn-ẹ̀yẹ tó pọ̀ jùlọ tí wọ́n jáde ní ilé-ìwé gíga.[1][2] Ó gbá bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n fún University of Oklahoma, ní àsìkò yìí Nancy Lieberman, aṣàyẹ̀wó bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n tí ilé-iṣẹ́ ESPN sọ wípé, dídarapọ̀ Ọlájùwọ́n sí ìkọ̀ rẹ̀ fún ìdíje tí ọdún 2006 sí 2007 yóò mú kí wọ́n ṣe àṣeyọrí fún ìdíje NCAA.[3]
Lọ́dún 2010, ó kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ ìròyìn láti Oklahoma University.[4]
Àṣàyàn iṣẹ́ rẹ̀ ní Oklahoma University
àtúnṣeSource[5]
GP | Games played | GS | Games started | MPG | Minutes per game |
FG% | Field goal percentage | 3P% | 3-point field goal percentage | FT% | Free throw percentage |
RPG | Rebounds per game | APG | Assists per game | SPG | Steals per game |
BPG | Blocks per game | PPG | Points per game | Bold | Career high |
Ọdún | Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n | GP | Àmìn ayò | FG% | 3P% | FT% | RPG | APG | SPG | BPG | PPG |
2006-07 | Oklahoma | 17 | 37 | 48.4% | 0.0% | 58.3% | 1.5 | 0.1 | 0.2 | 0.1 | 2.2 |
2007-08 | Oklahoma | 19 | 36 | 40.0% | 0.0% | 88.9% | 3.2 | 0.1 | 0.4 | 0.1 | 1.9 |
2008-09 | Oklahoma | 27 | 37 | 31.7% | 0.0% | 55.0% | 2.2 | 0.1 | 0.3 | 0.1 | 1.4 |
2009-10 | Oklahoma | 38 | 401 | 50.6% | 0.0% | 61.7% | 7.3 | 0.5 | 0.5 | 0.9 | 10.6 |
Career | 101 | 511 | 47.8% | 0.0% | 62.1% | 4.2 | 0.2 | 0.4 | 0.4 | 5.1 |
Ìgbìyànjú rẹ̀ nínú iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n
àtúnṣeChicago Sky yan Ọlájùwọ́n sí ipò méjìdínlọ́gbọ̀n nínú àwọn tó mọ bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n gbá jùlọ ní àgbáyé ní ìdíje lọ́dún 2010. [6] Lẹ́yìn èyí, ó dára pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n ní orílẹ̀ èdè Hungary, SEAT-Lami-Véd Győr,[7] àti ti Romania.[8]
Ní 2011 Ọlájùwọ́n padà sí WNBA, tí ó sìn tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn fún ikọ̀ Tulsa Shock, ibẹ̀ ló ti díje fún sáà ìdíje ọdún 2011 season.[9]
Nígbà ìsinmi, ó gba bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n fún Hapoel Rishon LeZion (Israel), ŽKK Novi Zagreb (Croatia),[10] BC Castors Braine (Belgium).[11] Ìkọ̀ Tulsa Shock dàá sílẹ̀ lọ́dún 2012.[12] Lẹ́yìn èyí, ó gba bọ́ọ̀lù fún Esportivo Ourinhos (Brazil),[13] àti Heilongjiang Chenneng (China).[14]
Ọlájùwọ́n gba ìsinmi lẹ́nu gbígbá bọ́ọ̀lù-ajùsáwọ̀n ní ìkọ̀ orílẹ̀ èdè Italy, Caja Rural Zamarat.[15]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Michael Kinney, A name to remember: Abi Olajuwon Archived October 8, 2007, at the Wayback Machine., December 6, 2006
- ↑ Tony Sellars, Olajuwon wants to make her own name Archived November 1, 2006, at the Wayback Machine., scout.com, February 9, 2006
- ↑ Terps top preseason Top 25, espn.com, accessed January 30, 2007
- ↑ http://www.emueagles.com/coaches.aspx?rc=1239 "Abi Olajuwon - Assistant Coach." Official Website of the Eastern Michigan Eagles. Accessed December 10, 2017.
- ↑ "NCAA Statistics". web1.ncaa.org. Retrieved 2017-08-28.
- ↑ "Olajuwon waived by Sky". ESPN.com. July 2, 2010. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ "SEAT Lami Ved Gyor adds Olajuwon to their roster". www.eurobasket.com. August 24, 2010. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ Nenciu, Andru; Fabian, Ciprian (March 1, 2011). "Fiica unei legende a NBA a ajuns la Satu Mare! Numele ei: "Născută în bogăţie şi iubită de toţi" :)". ProSport (in Èdè Romania). Retrieved October 18, 2016.
- ↑ Bailey, Eric (July 21, 2011). "Tulsa Shock release Marion Jones, sign former Sooner Abi Olajuwon". NewsOK.com. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ "Novi Zagreb adds Abi Olajuwon". www.eurobasket.com. January 13, 2012. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ Detroz, Christian (February 21, 2012). "Abi Olajuwon rejoint les Castors de Braine". Basketfeminin.com (in Èdè Faransé). Retrieved October 18, 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Moss, John (April 22, 2012). "Tulsa Shock Waive Former Sooner Abi Olajuwon". KTUL.com. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ Balassiano, Fábio (October 12, 2012). "Filha de lenda da NBA, Abi Olajuwon chega a Ourinhos para a Liga de Basquete Feminino". UOL Esporte (in Èdè Pọtogí). Retrieved October 18, 2016.
- ↑ "Abi Olajuwon agreed terms with Heilongjiang". www.eurobasket.com. December 11, 2012. Retrieved October 18, 2016.
- ↑ "Abi Olajuwon joins Caja Rural". www.eurobasket.com. July 13, 2013. Retrieved October 18, 2016.