Àdánidá
Àdánidá jẹ́ gbogbo ohun pátápátá tó wà ni ilé-ayé, gbogbo ìṣẹ̀lẹ̀ (òjò, àrá, ooru a.bb.lọ), gbogbo ohun ẹlẹ́mìí àti gbogbo èyí tí kò lẹ́mìí. Igbó, koríko, ẹranko, òkúta, ilẹ̀.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |