Àdìtú Olódùmarè
Àdìtú Olódùmarè jẹ́ orúkọ iwe ti D.O. Fagunwa kọ.
Ọ̀rọ̀ Àkọ́sọ
Ìwé ìtàn-àròsọ yìí wà fún tọmọdé tàgbà lọ́kùnrin lóbìnrin tí wọ́n mọ èdè Yorùbá kà dáadáa. Òun pẹ̀lú àwọn ìyóòkù rẹ̀ bíi Ògbójú Ọdẹ nínú Igbo Irúnmọlẹ̀, Ìrèké Òníbùdó, Ìrìnkèridò nínú Igbo Elégbèje àti Igbó Olódùmarè, tí D.O Fagunwa kọ jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára ìwé tí àwọn ọmọ Iléẹ̀kọ́ gíga yunifásítì tàbí Iléẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ni fún iṣẹ́ akadá lọ́pọ̀ ìgbà. Iṣẹ́ gbooro lórí ìwé bíi ìtúpalẹ̀, lámèyító, abbl bákan àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lè lo fún iṣẹ́ àpilẹ̀kọ fún àṣekágbá ẹ̀kọ́.
- D.O. Fágúnwà (2005) Àdììtú Olódùmarè Ibadan; Evans Brothers (Nigeria publishers) Limited, ISBN 978-126-239-7. Ojú-iwé 148.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |