Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Akáríayé
Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Káríayé (International Labour Organization; ILO) je ile-ise agbajo akariaye ti Agbajo awon Orile-ede Asokan to je mo oro osise, agaga opagun osise akariaye ati ise to niyi fun gbogbo aye.[1] Bi gbogbo awon omoegbe awon Orile-ede Asokan (185 ninu 193) ni won wa ni ILO.
Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Akáríayé International Labour Organization Organisation internationale du Travail Organización Internacional del Trabajo | |
---|---|
Irú | UN agency |
Orúkọkúkúrú | ILO |
Olórí | Juan Somavía |
Ipò | active |
Dídásílẹ̀ | 1919 |
Ibùjókòó | Geneva |
Ibiìtakùn | ilo.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ ILO Decent Work Agenda. Ilo.org. Retrieved on 2012-06-02.