Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Tógò
Àrùn COVID-19 dé sí orílẹ̀-èdè Togo ni oṣù kẹta ọdún 2020.[2]
COVID-19 pandemic in Togo | |
---|---|
Àrùn | COVID-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Togo |
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́ | Wuhan, Hubei, China via France or Germany |
Index case | Lomé |
Arrival date | 6 March 2020 (4 years, 9 months and 4 weeks) |
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 839 (as of 25 July)[1] |
Active cases | 237 (as of 25 July)[1] |
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 585 (as of 25 July)[1] |
Iye àwọn aláìsí | 17 (as of 25 July)[1] |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeNí ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Àmọ́ ó tó ọjọ́ Kẹtalélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣòkan àgbáyé létí.[3][4]
Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003,[5][6] Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ìtànkálé àrùn COVID-19 ń gbópọn si lójojúmọ́ tí ó sì ti ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpò ènìyàn lágbáyé.
Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ láwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan
àtúnṣeNí ọjọ́ kẹfa oṣù kẹta, orílẹ̀-èdè Togo ní àkọsílẹ̀ àkọ́kọ́ àrùn COVID-19. Ẹni tí ó kó àrùn náà wọ orílẹ̀-èdè náà jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Togo tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méjì lélógojì. Wọn fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé aláàárẹ̀ náà ti ṣe ìrìn-àjò lọ sí àwọn ìlú bí Germany, France, Turkey àti Benin, ṣáájú kí ó tó dárí padà sí orílẹ̀-èdè Togo. [7][8]
Orílẹ̀-èdè Togo ti ní akọsílẹ̀ mẹ́jọ lápapọ̀ awon ti o ni àrùn náà nígbà tí yóò fi di ọjọ́ ogún oṣù Kẹ́ta ọdún 2020. Arábìnrin tí ó kọ́kọ́ kó àrùn náà sí ti rí ìwòsàn gba. [9][10]
Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta, wọ́n ti àwọn pápákọ̀ òfurufú wọn pa láti tètè dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn náà lẹ́yìn tí wọn ríi awọn ẹ̀yán méje tí ó tún kó àrùn náà. Àwọn ará ìlú Lome, Tsevie, Kpalime àti Sokode wá ní ìgbélé fún ọ̀sẹ̀ méjì láti ọjọ́ ogún oṣù kẹta. [11][12]
Ní ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù kẹta, ẹ̀yán kàn papò dà láti ara àrùn náà. [13]
Ní ìparí oṣù kẹta, wọn tí ríi àwọn èèyàn mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tí ó kó àrùn náà, tí èèyàn kan ṣoṣo sì papò dà, àwọn mẹ́wàá sì rí ìwòsàn gbà. [14]
Ní oṣù kẹrin, wọn ríi àwọn ẹ̀yán méjìlèlọ́gọ́rin tí ó tún kó àrùn náà, èyí sì jẹ ki gbogbo àwọn tó ti ko àrùn náà je 116. Àwọn ẹ̀yán mẹsan sì papò dá, àwọn ẹ̀yán 65 sì rí ìwòsàn gba.[15]
Ní oṣù karùn-ún, àwọn èèyàn 326 tún kó àrùn náà, èyí sì jẹ ki gbogbo àwọn tó ti ko àrùn náà je 442. Àwọn ẹ̀eyán mẹ́rin kú ní oṣù náà, èyí sì jẹ ki gbogbo àwọn tí papò dá jẹ́ mẹ́tàlá, àwọn ẹ̀yán 211 sì rí ìwòsàn gba. [16]
Ní oṣù kẹfà, wọn ríi àwọn ẹ̀yán 208 tí ó tún kó àrùn náà, èyí sì jẹ ki gbogbo àwọn tó ti ko àrùn náà je 643. Èèyàn kàn kú ní oṣù náà, èyí sì jẹ ki gbogbo àwọn tí papò dá jẹ́ mẹ́rìnlá, àwọn ẹ̀yán 395 sì rí ìwòsàn gba. Awon èèyàn 234 síi ni àrùn náà ni ipari oṣù náà.[17]
Ni Oṣu Kẹsan ọdun 2021, Togo n gbooro si ipo pajawiri ilera titi di Oṣu Kẹsan 2022 ni atẹle igbesoke ni awọn ọran tuntun ti coronavirus ni awọn ọsẹ to ṣẹṣẹ. Wiwọle si awọn ile iṣakoso jẹ koko ọrọ si igbejade ti ikọja ajesara Covid-19 kan.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Coronavirus au Togo". covid19.gouv.tg (in Èdè Faransé). Archived from the original on 24 January 2021. Retrieved 25 July 2020.
- ↑ "Togo confirms 1st coronavirus case". www.aa.com.tr. Retrieved 2020-05-26.
- ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Togo confirms first case of coronavirus". Reuters. Archived from the original on 6 March 2020. Retrieved 6 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Togo confirms first case of coronavirus". The Jerusalem Post. Reuters. Archived from the original on 8 March 2020. Retrieved 11 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ First, Togo. "Coronavirus: Togo reports 8 new cases". www.togofirst.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 March 2020.
- ↑ "Togo : 8 nouveaux cas de Coronavirus confirmés". L-FRII (in Èdè Faransé). 20 March 2020. Retrieved 21 March 2020.
- ↑ "Coronavirus Update (Live): 301,100 Cases and 12,948 Deaths from COVID-19 Virus Outbreak - Worldometer". worldometers.info (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 March 2020.
- ↑ "Togo closes borders over coronavirus – FAAPA FR" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). FAAPA. Retrieved 21 March 2020.
- ↑ Médoune, SAMB (2020-03-27). "Coronavirus: Journalist Dominique Aliziou, first case of death linked to COVID-19 in Togo". Panafrican News Agency (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-11.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 72" (PDF). World Health Organization. 1 April 2020. p. 8. Retrieved 14 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 102" (PDF). World Health Organization. 1 May 2020. p. 6. Retrieved 14 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 133" (PDF). World Health Organization. 1 June 2020. p. 7. Retrieved 14 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 163" (PDF). World Health Organization. 1 July 2020. p. 7. Retrieved 14 July 2020.