Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Mẹ̀lílà
Wọ́n kọ́kọ́ kéde Ìbẹ́sílẹ̀ Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní Mẹ̀lílà lórílẹ̀ èdè Spain lóṣù kẹta ọdún.
COVID-19 pandemic in Melilla | |
---|---|
Àrùn | COVID-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Mẹ̀lílà |
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́ | Wuhan, Hubei, China via Spain |
Arrival date | ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2020 (4 years, 8 months, 3 weeks and 1 day) |
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 107 |
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 27 |
Iye àwọn aláìsí | 2 |
Bí àrùn náà ṣe ń jàkálẹ̀ láti ìgbà dé ìgbà
àtúnṣeOṣù kẹta ọdún 2020
àtúnṣeArákùnrin kan tí ó rìnrìn-àjò láti àgbègbè kan tí wọ́n ń pè ní Iberian Peninsula ló kó àrùn náà wọ Mẹ̀lílà, àgbègbè àwọn ọmọ adúláwò Áfríkà ní orílẹ̀ èdè Spain. [1]
Oṣù kẹrin ọdún 2020
àtúnṣeNígbà tí ó má fi di ọjọ́ kẹrìndínlógùn oṣù kẹrin ọdún 2020, ó ti tó iye ènìyàn mẹ́tàlélọ́gọ́rùn-ún tí wọ́n ti kéde wọn pé wọ́n kó àrùn Covid-19. Wọ́n kéde ẹni mẹ́tàdínlọ́gbọ́n, 27 tí wọ́n wòsàn, tí ẹnì méjì péré sìn kú.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ministerio de Sanidad, Consumo y Bienestar Social - Profesionales - Teléfonos de información - Coronavirus". www.mscbs.gob.es. Archived from the original on 4 April 2020. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "Un positivo más en COVID-19 y tres nuevos recuperados en Melilla". El Faro de Melilla (in Èdè Sípáníìṣì). 2020-04-15. Retrieved 2020-04-16.