Àkójọpọ̀ àwọn oúnjẹ tí a le rí láti ara ẹran Ẹlẹ́dẹ̀

Àtòjọ àwọn oúnjẹ láti ara ẹlẹ́dẹ̀

Èyí ni àtòjọ àwọn oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ tí a le rí láti ara Ẹlẹ́dẹ̀. Ẹran Ẹlẹ́dẹ̀ ni èyí tí a rí láti ara ẹlẹ́dẹ̀ ilé (Sus domesticus). Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹran tí wọ́n ń jẹ lágbàáyé,[1] pẹ̀lú ẹ̀rí láti ara ọ̀sìn ẹran ẹlẹ́dẹ̀ ní nǹkan bíi 5000 BC sẹ́yìn. Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tútù jẹ́ èyí tí a le sè tí a sì le gbé pamọ́.

Roasted baby back pork ribs

Jíjẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀ jẹ́ èwọ̀ nínú ẹ̀sìn Judaism, Islam, àti àwọn ọmọlẹ́yìn Kirisitì bíi Seventh-day Adventism.

Jíjẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tútù jẹ́ èyí tí ó léwu fún ìlera àwa ẹ̀dá láwùjọ èyí tí ó sì le fa àìsàn tí à ń pè ní trichinosis. Ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ẹ̀ka tí ó ń rí sí ètò ohun ọ̀gbìn gba àwọn ènìyàn ní ìyànjú láti máa se ẹran ẹlẹ́dẹ̀ jinná dáadáa kí wọ́n ó sì fi sílẹ̀ fún bíi ìṣẹ́jú mẹ́ta láti tútù lẹ́yìn tí wọ́n bá sè é tán.

Àdàkọ:Compact ToC

Oúnjẹ ẹran ẹran ẹlẹ́dẹ̀

àtúnṣe

Àdàkọ:Dynamic list

 
Ẹlẹ́dẹ̀ bakkwa, èyí tí ṣe láti ara ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tí a ṣe lọ́jọ̀ kí á tó sè é, ọgbọ́n àtinúdá yìí wá láti orílẹ̀-èdè China àtijọ́ [2]
 
Char siu jẹ́ ẹran ẹlẹ́dẹ̀ sísun tí ó gbajúmọ̀ ní Cantonese.[3]
 
Cha siu bao[4]
 
Ẹlẹ́dẹ̀ Dongpo

jẹ́ oúnjẹ àwọn Hangzhou[5] èyí tí a máa ń dín kí á tó sè é.

 
Geera pork
 
Judd mat Gaardebounen – Ẹlẹ́dẹ̀ sísun
 
Kaeng hang le
 
"Kilayin"
 
Red-cooked

(soy-braised)

 
Minced pork rice
 
Nam tok mu jẹ́ oúnjẹ àwọn Thai tí a ṣe láti ara ẹlẹ́dẹ̀. * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link * Àdàkọ:Annotated link
 
Ẹlẹ́dẹ̀ sísun lórí aya rán
 
Pork chop
 
kórópọ̀n Ẹlẹ́dẹ̀

àti ọbẹ̀ jíńjà, ó jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Cantonese

 
Pork rica-rica
 
Roujiamo sísè
 
Rullepølse
 
Stegt flæsk sauce
 
pork tenderloin sandwich
 
Tokwa't baboy

Wò pẹ̀lú

àtúnṣe

Àdàkọ:Portal box

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Raloff, Janet. Food for Thought: Global Food Trends. Science News Online. May 31, 2003.
  2. Leistner, Lothar (1999). Lund, Barbara M.. ed. The microbiological safety and quality of food: Volume 1. Gaithersburg: Aspen Publishers. pp. 306. ISBN 978-0-8342-1323-4. 
  3. TVB. "TVB." 廣東菜最具多元烹調方法. Retrieved on 2008-11-19.
  4. Hsiung, Deh-Ta. Simonds, Nina. Lowe, Jason. [2005]. The food of China: a journey for food lovers. Bay Books. ISBN 978-0-681-02584-4. p24.
  5. Cannon, Gwen, ed (2010). Michelin Must Sees Shanghai. London: Michelin Apa Publications. pp. 133. ISBN 978-1-906261-99-3. https://books.google.com/books?id=PjlQTjxgcDoC. 
àtúnṣe

Àdàkọ:Lists of prepared foods Àdàkọ:Meat Àdàkọ:Cuisine