Àkójọpọ̀ ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ Ghana

Oríṣi ọdún ìbílẹ̀ ní Ghana

Àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Ghana wọ́n máa ń ṣe àwọn ọdún yìí fún onírúurú àwọn ìdí kan sí èkejì bí ó bá ṣe kan ẹ̀yà kan sí tàbí irúfẹ́ àṣà bẹ́ẹ̀. Àwọn ọdún kọ̀ọ̀kan ló ní àwọn ìtàn tí ó rọ mọ́ wọn èyí tí ó máa ń rọ̀ mọ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan. Àpẹẹrẹ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni; ebi, Ìṣípòpadà, láti fọ ìlú mọ́, abbl...

Ìdí tí wọ́n fi máa ń ṣe ayẹyẹ

àtúnṣe

Àwọn ìwúlò pàtàkì tí ó wà fún ṣíṣe ayẹyẹ kan:

  • Gbígbèèrò àwọn iṣẹ́ àkànṣe fún ìdàgbàsókè ìlú: Wọ́n máa ń lo àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ láti pàdé papọ̀ pẹ̀lú àwọn ará ìlú láti le jíròrò lórí àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí ó le mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ.
  • Fífọ àwọn òrìṣà mọ́: Wọ́n máa ń lo àkókò àti ìgbà yìí láti tún ojúbọ àwọn òrìṣà ṣe kí wọ́n ó sì ṣe àwọn ètùtù tí ó ṣe kókó.
  • Ìdúpẹ́: Wọ́n máa ń lo àwọn ayẹyẹ ọdún láti fi dúpẹ́ lọ́wọ́ Elédùmarè àti àwọn òrìṣà fún ìtọ́sọ́nà àti ìdáàbòbò wọn.
  • Ipa òṣèlú àti ti ìjọba àpapọ̀: Àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ èèkàn nínú ìlú àti àwọn tí wọ́n ń bẹ ní ìṣàkóso ìlú ni wọ́n máa ń fi ìwé pè láti wá ṣàlàyé nípa ètò tí ìjọba ni fún àwọn ará ìlú.
  • Láti paná ìjà:Wọ́n máa ń lo àwọn ọdún ìbílẹ̀ láti parí ìjà láàrin àwọn ẹbí, ará, ọ̀rẹ́ àti ojúlùmọ̀ kí àlàáfíà lè jọba.
  • Láti gbé àṣà àti ìrìnnà afẹ́ lárugẹ: Àwọn ayẹyẹ ìbílẹ̀ kan wà ní orílẹ̀ èdè Ghana tí ó máa ń fa ojú àwọn ènìyàn láti orílẹ̀ èdè mìíràn wá. Lára àwọn ayẹyẹ bẹ́ẹ̀ ni a ti rí - Ayẹyẹ ọdún Aboakyir. Ìrìnàjò afẹ́ losi orílẹ̀ èdè Ghana jẹ́ ọ̀nà kẹta tí owó ń gbà wọlé láti ilẹ̀ òkèèrè

Àkójọpọ̀ àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ àti oṣù tí wọ́n máa ń ṣe wọ́n

àtúnṣe
Ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Ghana Àwọn ẹ̀yà tí wọ́n máa ń ṣe é
Bakatue[1] Elmina (Fante)
Homowo[2] Ga
Aboakyer[3] Efutu (Winneba)
Kundum[4] Nzema[5]
Fao NavrongoÀdàkọ:Cn
Kpini Chugu (Guinea fowl Festival) Dagombas, Mamprusis, Nanumbas, Kokombas and Basaris[6]
Ohum[7] Akim,[8] Akuapem[9]
Hogbetsotso[10] Anlo[11]
Ngmayem Krobo[12]
Volo (Me/Lomo) Volos
Yam[13] Ho[14]
Buɣum Chuɣu (Fire Festival)[15][16]al) Dagomba[17] Dagbon, Gonja, Mamprusi and Nanumba
Beng Gonja[18]
Lukusi Ve (Near Hohoe)
Danyiba Kpando[19]
Fetu Afahye[20] Oguaa[21] (Cape Coast)
Adae Kese Ashanti[22] Etc.
Adae[23] Asante,[21]Akim,[8] Akwamu[24]
Asafotufiam[25] Ada[26]
Dzawuwu Festival[27] Agave[28]
Fiok[29] Builsa
Apafram[30] Akwamu[31]
Osudoku Festival[32] Asutsuare[33]
Afenorto Festival[30] Mepe[34]
Papa Festival[35] Kumawu[36]
Opemso FestivalÀdàkọ:Cn Kokofu-Anyinam
Ɔvazu FestivalÀdàkọ:Cn Akposo
Damba festival Dagomba people, Gonja, Mamprusi

Àkójọpọ̀ tí ó wà ní ìsàlẹ̀ yìí ni àwọn ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀, àwọn ọdún ẹ̀sìn tí wọ́n wà fún ìrántí tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún ní orílẹ̀-èdè Ghana. [37] Àkójọpọ̀ yìí le má kún fún gbogbo àwọn ọdún tí wọ́n ń ṣe lórílẹ̀-èdè Ghana.

Fún ìṣèrántí ọdún ọ̀gbìn

àtúnṣe

Fún ìṣèrántí Ìṣípòpadà

àtúnṣe

Fún ẹ̀sìn

àtúnṣe

Àwọn tó kù

àtúnṣe

Oti Region)]]

  • Ɔvazu (Akposokubi) Oti Region, formally Volta/Trans-Volta Togoland

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Bakatue Festival , 2019 - GWS Online GH". www.ghanawebsolutions.com. Retrieved 2019-01-26. 
  2. "Homowo Festival". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-26. 
  3. "Aboakyer Festival". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-26. 
  4. "Kundum Festival". www.travel-to-discover-ghana.com. Retrieved 2019-01-26. 
  5. "National Commission On Culture". www.ghanaculture.gov.gh. Retrieved 2019-01-27. 
  6. "The Northern Region of Ghana - ghanagrio.com - ghanagrio.com". www.ghanagrio.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-09-22. Retrieved 2019-10-02. 
  7. "OHUM STARTS". Modern Ghana. 2012-08-28. Retrieved 2019-01-27. 
  8. 8.0 8.1 "Akyem People of Ghana.". Africani Sankofa. 2017-11-22. Archived from the original on 2019-01-27. Retrieved 2019-01-27. 
  9. "Choirmaster for Awukugua Ohum". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-23. 
  10. "Hogbetsotso Festival". www.travel-to-discover-ghana.com. Retrieved 2019-01-26. 
  11. "The Anlo-Ewe people of Ghana". This Is Africa Lifestyle. 2017-07-10. Archived from the original on 2019-01-27. Retrieved 2019-01-27. 
  12. "The Krobo People of Ghana to 1892: A Political and Social History". Ohio University Press • Swallow Press. Retrieved 2019-01-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  13. "Asogli promises another exciting yam festival this year". www.myjoyonline.com. 2017-09-06. Retrieved 2019-01-26. 
  14. "Ghana Districts: A repository of all Local Assemblies in Ghana". www.ghanadistricts.com. Retrieved 2019-01-27. 
  15. "Ghana Festivals". ghanakey.com. Archived from the original on 2021-08-03. Retrieved 2020-01-21. 
  16. Cof, Katja (2016-03-05). "Buɣum Chuɣu Fire Festival in Northern Ghana". Safari Junkie. Archived from the original on 2019-01-26. Retrieved 2019-01-26. 
  17. "Dagomba kingdom | historical kingdom, Africa". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27. 
  18. "A Brief History of Northern Ghana - Focus on Gonja". www.ghanaweb.com. 30 November 2001. Retrieved 2019-01-27. 
  19. "Kpando Municipal Assembly – Official Website of Kpando Municipal Assembly". Retrieved 2019-01-27. 
  20. "Oguaa Fetu Afahye Festival, Cape Coast". Afro Tourism. 2017-03-10. Archived from the original on 2021-06-12. Retrieved 2019-01-26. 
  21. 21.0 21.1 "Oguaa Fetu Afahye Festival, Cape Coast". Afro Tourism. 2017-03-10. Archived from the original on 2021-06-12. Retrieved 2019-01-27. 
  22. "Asante | people". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27. 
  23. "Adae | Akan festival". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27. 
  24. "Ghana Ethnic Groups, Akwamu". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-01-27. 
  25. "About". Ada Asafotufiami Festival. 2010-12-13. Retrieved 2019-01-26. 
  26. "ADA PEOPLE: THE TRADITIONALIST DANGME PEOPLE AND THEIR UNIQUE ASAFOTUFIAMI FESTIVAL". ADA PEOPLE. Retrieved 2019-01-27. 
  27. Editor (2016-02-24). "Festivals in Ghana". touringghana.com. Retrieved 2019-01-26. 
  28. "Agave Afedome - GhanaPlaceNames". sites.google.com. Archived from the original on 2020-10-21. Retrieved 2019-01-27. 
  29. "FESTIVALS OF GHANA". www2.gsu.edu. Archived from the original on 2019-01-11. Retrieved 2019-01-26. 
  30. 30.0 30.1 Dzaho, Jerome. "Festivals". Ghana Tourism Authority. Archived from the original on 2019-01-27. Retrieved 2019-01-26. 
  31. "Akwamu | historical state, Africa". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-01-27. 
  32. "Osudoku Aadegbor Festival Launched". Modern Ghana. 2018-08-07. Retrieved 2019-01-26. 
  33. "Figure 1: Shai Osudoku District Map (where Asutuare Area Council lies)....". ResearchGate. Retrieved 2019-01-27. 
  34. "Mepe Community Site". mepe.objectis.net. Retrieved 2019-01-27. 
  35. "Papa Festival". TheFreeDictionary.com. Retrieved 2019-01-26. 
  36. "National Commission On Culture". www.ghanaculture.gov.gh. Retrieved 2019-01-27. 
  37. "Festivals". GhanaWeb. Retrieved 23 October 2014. 
  38. "Festivals in Ghana". Dear Ghana. Retrieved 23 October 2014. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  39. "Festivals in Ghana". www.ghanaweb.com. Retrieved 27 December 2011. 

Àdàkọ:Ghana topics