Àkúdàáyà
Àkúdàáyà gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ Yorùbá ni ìṣípòpadà òkú ènìyàn sí àlàyè ènìyàn ní àgbègbè tí wọ́n kò mọ̀ ọ́n tàbí lọ́dọ̀ ẹni tí ó ti mọ̀ pé irú ẹni bẹ́ẹ̀ tí kú.[1] [2] [3]
Ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa Àkúdàáyà
àtúnṣeYorùbá ní ìgbàgbọ́ pé Àkúdàáyà wà. Wọ́n gbàgbọ́ pé ẹni tí ó bá kú láìtọ́jọ́ tàbí wọ́n pa á tàbí ó kúkú nípa ìjàm̀bá máa ń ní àǹfààní lọ́dọ̀ Elédùmarè láti ṣípò padà sí àlàyè, ṣùgbọ́n sí àgbègbè mìíràn tí wọ́n kò ní mọ̀ pé òkú ní. Lọ́jọ́kọ́jọ́ tí ẹni tí ó bá mọ̀ ón bá rí I, ọjọ́ náà ni yóò pòórá kúrò níbi náà. Ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé irú ẹni bẹ́ẹ̀ lè tún gbé ayé kí ó sì ṣe gbogbo nǹkan tí ènìyàn ń ṣe, pàápàá jùlọ àyànmọ́ rẹ̀ tí kò ì tí ì múṣẹ kí ó tó kú. [4] [5] [6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Publishing, Scientific Research (2015-12-09). "An Evaluation of the Akure Yorùbá Traditional Belief in Reincarnation". Open Journal of Philosophy 06. doi:10.4236/ojpp.2016.61007. https://www.scirp.org/html/7-1650647_63610.htm. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "The Araba Agbaye: The Akudaaya". ORISHADA. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "Akudaaya (reincarnation), The Yoruba Belief That Is No More. - Culture". Nigeria. 2020-01-02. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "Academic search engine for paper". Scinapse. 2019-12-30. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "Meaning of Akudaaya". Nigerian Dictionary. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "AKUDAAYA : THE LIVING DEAD - MaxwellAyo". Wattpad. 2016-12-28. Retrieved 2020-01-02.