Àmàlà
Àmàlà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn oúnjẹ tó gbajúmọ̀ nínú àwọn oúnjẹ ìran Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Èlúbọ́ iṣu, gbágùúdá tàbí ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni wọ́n fi máa a ṣe Àmàlà .
[1]A o ti be̩,fo̩, pelu sisa si orun is̩u tabi paki ti afe̩ lo fun elubo̩ àmàlà. Latara wipe is̩u ti a fe̩ lo fun elubo̩ ti gbe̩ ni àmàlà fi ni awo̩ dudu.[2][3]Àmàlà jẹ ounjẹ ti o wọpọ ni jijẹ laarin eya Yoruba ni Naijiria.[4]Oriṣiriṣi ọbẹ la le fijẹ pẹlu, ọbẹ bi ẹfọ, ila, ọgbọnọ, ẹgusi, ewedu, gbẹgiri ati bẹ bẹ lọ.
Àmàlà pe loriṣiriṣi bi àmàlà iṣu, àmàlà lafun ati àmàlà ọgẹdẹ.
Awo̩n Ito̩kasi
àtúnṣe- ↑ Ferris, R. S. B.; Uwaegbute A. C.; Osho S. M.; Obatolu V. A. (1995). "Acceptability and chemical evaluation of fortified yam (Discorea spp.) products.". Postharvest technology and commodity marketing: proceedings of a postharvest conference 2 Nov. to 1 Dec. 1995 (Accra, Ghana): 172. ISBN 978-978-131-111-6. https://books.google.com/books?id=bIsz-PA75b4C&pg=PA172.
- ↑ Balogh, Esther (1989). "History and perspectives of stable foods in Africa". Oxford Symposium on Food & Cookery. p. 51. https://books.google.com/books?id=I15eJt6U3gMC&pg=PA51.
- ↑ Dumont, Roland (2006). Biodiversity and Domestication of Yams in West Africa: Traditional Practices Leading to Dioscorea Rotundata Poir. Editions Quae. p. 28. https://books.google.com/books?id=uViWez_aaQcC&pg=PA28.
- ↑ Roots, Tubers, Plantains and Bananas in Human Nutrition. Rome: Food and Agriculture Organization of the United Nations. 1990. p. 68. https://books.google.com/books?id=wRIIf11K3rUC&pg=PA68.