Àmì ẹ̀yẹ Lámèyítọ́ Fíímù Nollywood àti ilẹ̀ Adúláwọ̀
Àmì ẹ̀yẹ lámèyítọ́ Fíímù Nollywood àti ilẹ̀ Adúláwọ̀ jẹ́ ayẹyẹ tí ó má ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún fún àwọn òṣèré fíímù àti sinima àgbéléwò nílẹ̀ Adúláwọ̀. Wọ́n ti ń ṣé rí ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà láti ìgbà tí wọ́n ti da sílẹ̀ láti ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù Kẹ́jọ, ọdún 2011 (September 17, 2011).
Nollywood and African Film Critics Awards | |
---|---|
2012 Best Actress in a Lead Role (Diaspora) | |
Bíbún fún | Outstanding Achievement in African cinema |
Látọwọ́ | Nollywood Film Critics USA |
Orílẹ̀-èdè | United States |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 2011 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | africannafca.com |
Ayẹyẹ àmì ẹyẹ yìí tí ẹlẹ́kẹ̀ẹ́rin irú rẹ̀ wáyé ní ọjọ Kẹtàlá oṣù Kẹsàán, ọ̀dún 2014 (13 September 2014) ní gbọ̀gàn sininmá Saban,Beverly Hills, ní California.[1][2][3]
Irú rẹ̀ ẹlẹ́kẹfà wáyé ní ọ̀jọ́ Kọkàndínlógún oṣù Kọkàn ọdún 2016 ní gbọ̀gàn ceremony was held on November 19 at Alex ,Glendale, California. Tí àwọn òṣèré bí Stephanie Okereke, Mike Ezuruonye àti Obi Emelonye wà lára àwọn fi ẹ̀bùn nàá ṣèfà jẹ.[4]
Àwọn ìsọ̀rí tí ó pín sí
àtúnṣeÀwọn wọ̀nyí ni ìsọ̀rí tí ayẹyẹ ẹ̀bùn náà pín sí ní ọdún 2014 :
- Òṣèrékùnrin tó dára jùlọ tó ṣíwájú eré
- Òṣèrébìnrin tó dára jùlọ tó ṣíwájú eré
- Òṣèrékùnrin tó dára jùlọ tó ṣíwájú eré tó jẹ́ amúgbá lẹ́gbẹ̀ẹ́
- Òṣèrébìnrin tó dára jùlọ tó aṣíwájú eré tó jẹ́ amúgbá lẹ́gbẹ̀ẹ́
- Òṣèré tó dára jùlọ tí fíímù ṣèlérí rẹ̀
- Òṣèré tó dára jùlọ nínú fíímù ilẹ̀ òkèrè
- Òṣèrém-ọdé tó dára jùlọ nínú fíímù
- Olùdarí tó dára jùlọ
- Fíímù tó dára jùlọ̀
- Fíímù Aláwàdà tó dára jùlọ
- Fíímù eré Oníṣe tó dára jùlọ
- Ìró tàbì orin tó dára jùlọ
- Àwòrán tó dára jùlọ
- Ìtàgé tó dára jùlọ
- Àtúnṣe tó dára jùlọ
- Best Original Score
- Atúniṣe tó dára jùlọ
- Ìmúra tó dára jùlọ
- Eré Ìbílẹ̀ tó dára jùlọ
- Eré ilẹ̀ òkèrè tó dára jùlọ
- Fíímù tí ó tà jùlọ
- Amóhùnmáwòrán/ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nu wò àti eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tó dára jùlọ
Àwọ eré tí wọ́n ṣe nílùú mìíràn
- Fíìmù tí wọ́n ṣe nílùú míràn tó dára jùlọ
- Eré oníṣe tí wọ́n ṣe nílùú míràn tó dára jùlọ
- Òṣèrékùnrin tó ṣíwájú tó dára jùlọ nínú eré tí wọ́n ṣe nílùú míràn
- Òṣèrébìnrin tó ṣíwájú ntó dára jùlọ nínú eré tí wọ́n ṣe nílùú míràn
- Òṣèrékùnrin tó dára jùlọ tó ṣíwájú eré tó jẹ́ amúgbá lẹ́gbẹ̀ẹ́ nínú fíímù tí wọ́n ṣe nílùú míràn
- Òṣèrékùnrin tó dára jùlọ tó ṣíwájú eré tó jẹ́ amúgbá lẹ́gbẹ̀ẹ́ nínú fíímù tí wọ́n ṣe nílùú míràn
- Adarí tódára jùlọ
- Adarí tódára jùlọ nínú fíímù ilẹ̀ òkèrè
- Òṣèré tó dára jùlọ nínú fíímù ilẹ̀ òkèrè
- Òṣèrékùnrin tó jẹ́ ààyò
- Òṣèrébìnrin tó jẹ́ ààyò
- Adarí tó jẹ́ ààyò
- Alákọsílẹ̀ ojú-pátáló tó jẹ́ ààyò
- Favorite Original Score
- Favorite Short Film/Trailer
- Òṣèrékùnrin tọ́ dára jùlọvtí fíímù ṣèlérí rẹ̀
- Òṣèré tó dára jùlọ nínú ọdún
- Orin tó dára jùlọ nínú ọdún
- Fíímù ajẹmáwùjọ tó dára jùlọ
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Susan Peters up for NAFCA Awards Nominations". vanguardngr.com. August 20, 2011. Retrieved 15 July 2014.
- ↑ "Somewhere in Africa tops NAFCA Awards nomination list". peacefmonline.com. 1 September 2011. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 15 July 2014.
- ↑ "Full list of Nominees at the 1st NAFCA Awards". 26 August 2011. Archived from the original on 7 October 2018. Retrieved 15 July 2014.
- ↑ Aduwo, Bola (November 22, 2016). "LIST OF WINNERS OF THE 2016 NAFCA AWARDS". Nollywood Access. Archived from the original on September 7, 2017. Retrieved November 12, 2018.