Àrùn jẹjẹrẹ ọmú

Àdàkọ:Infobox medical condition (new)Àrùn jẹjẹrẹ ọmú jẹ àrùn tó jẹyọ láti araàwọn ohun àsopọ tó wà nínú ọmú[1] Lára àwọn àmì àìsàn jẹjẹrẹ ní níní ééwo nínú ọmú, ìyàtọ nínú ìrísí ọmú, níní àwọ̀ tó dàbí èpo ọ̀sàn, kí ìkókó máa kọ omi ọmú, kí omi ọmú máa da láìfọ́mọ lọ́mú, tí orí ọmú bá kojú sínú, kí àwọ máa pọ kó sì máa gbẹ.[2] [3] Nínú àwọn àrùn tó máa ń tàn ká láti ọnà jínjìn, ó ṣeé ṣe kí ìrora wà nínú egungun, kí ibì kan nínú ara máa wú, àìlemí dáadáa, tàbí kí ara máa pọ́.[4]

Àrùn jẹjẹrẹ ọmú

Àwọn okùnfà àrùn jẹjẹrẹ ọmú ní sísanrà jù, àìṣe eré-ìdárayá, ọtí àmujù, lílo ògùn láti máa ṣe nǹkan oṣù nígbà tí èèyàn ti wà ní  ọjọ-orí tí kò lè ṣe nǹkan oṣù mọ, títètè bẹ̀rẹ̀ nǹkan oṣù fún ọmọ tí ọjọ́ orí rẹ kéré, pípẹ́ bímọ àti kí èèyàn má bímọ rárá, ọjọ orí, tí àrùn jẹjẹrẹ bá wà nínú ìran, àti nínú ẹbí. Nínú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ti ṣẹlẹ̀ rí.[3][5] Bí ìdá 5-10% èèyàn ni wọn jogún rẹ, Àyípadà BRCA náà wà níbẹ̀.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Breast Cancer". NCI. January 1980. Archived from the original on 25 June 2014. Retrieved 29 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Breast Cancer Treatment (PDQ®)". NCI. 23 May 2014. Archived from the original on 5 July 2014. Retrieved 29 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. 3.0 3.1 3.2 "Breast Cancer Treatment (PDQ®)". NCI. 23 May 2014. Archived from the original on 5 July 2014. Retrieved 29 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Breast cancer (1. ed.). Oxford: Oxford University Press. 2009. p. Chapter 13. ISBN 978-0-19-955869-8. https://books.google.com/books?id=as46WowY_usC&pg=PT123. 
  5. World Cancer Report 2014. World Health Organization. 2014. pp. Chapter 5.2. ISBN 978-92-832-0429-9.