Ìwé Kíkà

Ìwé kíkà

Àsà iwé kíkà se pàtàkì nítorí pé ó je ìpìlè fún imo ati ìserere ninu eko kiko. Pelu aniyan l'orisisrisi ti o je mo mimo ko ati mimo ka, opolopo orlleede ni o ti gbaju mo eto ilana iwe kika ti o yaranti.[1]

Ni ida keji, asiko ti nkan ba din ku je asiko ti nkan naa ba ti n baje diedie tabi ti o ti fe ku bi efin. O tun je igba ti nkan ba ti d'enu k'ole, ti o n kere si tabi ti ko se dede mo.[2]

Lati igba de igba ni awon eyan ti n beere, kini idi ti iwe kika fi se pataki. Iwe kika je okan lara awon ona pataki ti a fi n mo nipa aye ti o yi wa ka. O ma n je ki a dagba ninu ogbon, ninu iwuwasi, ati nipa ise opolo. Gbogbo iwe lo ma n fun ni ni anfaani lati ko nkan tuntun ati lati s'awari ero tuntun. Iwe kika ma n fun ni ni alekun imo ati pe o ma n je ki opolo ji pepe.[3]


Ní àwon ìlú tí ó ti ní ìlosíwájú tó gbámúsé bi ilè America ìwé kíkà láti kékeré je àsà tí kò se e f'owó ró séyìn. Kódà òpòlopò òbí ni ó ma n gbìyànjú láti ka ìwé fún àwon omo won kí wón tó f'ojú ba orun ní alé.


Iwé kíkà dára lópòlopò fún àwon òjè wéwé wa, pàápàá jùlo àwon iwé aláwòrán tó ní àló l'orisirisi tí n kó ni l'ógbón tí ó sì n fún ni l'òye.

  1. Reading culture is a foundation skill for learning and academic achievement, and in the wake of worldwide concerns with literacy rates, many nations have turned their attention towards reading instruction and strategies.
  2. https://www.blueprint.ng/decline-in-reading-culture-in-nigeria/#:~:text=Decline%20on%20the%20other%20hand%20is%20the%20period%20during%20which%20something%20is%20deteriorating%20or%20approaching%20its%20end.%20It%20is%20also%20the%20downward%20movement%2C%20fall%2C%20weakness%2C%20reduction%20or%20diminution%20of%20activity.
  3. https://www.blueprint.ng/decline-in-reading-culture-in-nigeria/#:~:text=From%20time%20to,makes%20you%20smarter.