Àsìá ilẹ̀ Gùyánà je asia orile-ede. je ami opa ase ati ogun. je alawo marun; Pupa, Funufun, Esuru, Dudu ati Eweko. Awo pupa ti o duro fun iyapada daada, awo funfun ti o duro fun odo ati omi ti o mo kanga, esuru ti o duro fun wara ati oro orile ede naa, Dudu duro fun Ifarada awon omo orile ede naa ati awo eweko ti oduro fun eto ogbin ti o fese mule. .


ItokasiÀtúnṣe