Àtòjọ Àwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè Cameron
Èyí ni Àtòjọ Àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Cameron láti ìgbà tí wọ́n ti gba òmìnira lọ́wọ́ Orílẹ̀-èdè Faransé lọ́dún 1960 títí di òní yìí.
Ènìyàn méjì péré ló ti jẹ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Cameron lẹ́yìn òmìnira wọn.
Ààrẹ tó wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́ ni Paul Biya. Ó ti wà lórí oyè láti Ọjọ́ kẹfà oṣù kọkànlá ọdún 1982 [1]
Àtòjọ Àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Cameron
àtúnṣeàrokò ìdámọ̀
àtúnṣe- Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú
- Cameroonian Union (UC)
Àwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè Cameron
àtúnṣeNo. | Portrait | Name (Birth–Death) |
Term of office | Political party | Election | Prime Minister(s) | ||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Took office | Left office | Time in office | ||||||
Republic of Cameroun | ||||||||
1 | Ahmadou Ahidjo (1924–1989) | 5 May 1960 | 1 October 1961 | 1 year, 149 days | [[Cameroonian Union|Àdàkọ:Cameroonian Union/meta/shortname]] | – | Himself Assalé | |
Federal Republic of Cameroon | ||||||||
(1) | Ahmadou Ahidjo (1924–1989) | 1 October 1961 | 2 June 1972 | 10 years, 245 days | [[Cameroonian Union|Àdàkọ:Cameroonian Union/meta/shortname]] [[Cameroonian National Union|Àdàkọ:Cameroonian National Union/meta/shortname]] | 1965 1970 | East Cameroon Assalé Ahanda TchounguiÀdàkọ:Hr West Cameroon Foncha Jua Muna | |
United Republic of Cameroon | ||||||||
(1) | Ahmadou Ahidjo (1924–1989) | 2 June 1972 | 6 November 1982 (resigned.) | 10 years, 157 days | [[Cameroonian National Union|Àdàkọ:Cameroonian National Union/meta/shortname]] | 1975 1980 | Biya | |
2 | Paul Biya (born 1932) | 6 November 1982 | 4 February 1984 | 1 year, 90 days | [[Cameroonian National Union|Àdàkọ:Cameroonian National Union/meta/shortname]] | – | Maigari Ayang | |
Republic of Cameroon | ||||||||
(2) | Paul Biya (born 1932) | 4 February 1984 | Incumbent | 40 years, 317 days | [[Cameroonian National Union|Àdàkọ:Cameroonian National Union/meta/shortname]] [[Cameroon People's Democratic Movement|Àdàkọ:Cameroon People's Democratic Movement/meta/shortname]] | 1984 1988 1992 1997 2004 2011 2018 | Hayatou Achu Musonge Inoni Yang |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Presidents Of Cameroon". WorldAtlas. Retrieved 2020-02-11.