Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Èyí ni Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde tí wọ́n sìn ń tà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Títí di 2014, iye ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n wà lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà jẹ́ 1,331.[1]

Mẹ́wàá tó gbajúmọ̀ káàkiri jùlọ nínú àwọn ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà àtúnṣe

Àwọn wọ̀nyí ni mẹ́wàá nínú àwọn ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ jùlọ ní títàn káàkiri lóòjọ́ lọ́sẹ̀, tí kìí ṣe ọ̀fẹ́. [2]

Rank Orúkọ Ìwé-ìròyìn Àgbègbè tí wọ́n wà Olú ìlú tàbí ìpínlẹ̀ tí wọ́n wà Àpapọ̀ iye tí wọ́n ń gbé jáde Olùdásílẹ̀ Orúkọ Ìṣẹ̀dá lẹ̀ rẹ̀
1 USA Today McLean, Virginia Virginia 1,621,091 Gannett Company  
2 The Wall Street Journal New York City New York 1,011,200 News Corp  
3 The New York Times New York City New York 483,701 The New York Times Company  
4 New York Post New York New York 426,129 News Corp  
5 Los Angeles Times Los Angeles California 417,936 Nant Capital  
6 The Washington Post Washington D.C. District of Columbia 254,379 Nash Holdings  
7 Star Tribune Minneapolis Minnesota 251,822 Star Tribune Media Company  
8 Newsday Melville New York 251,473 Newsday Media Group  
9 Chicago Tribune Chicago Illinois 238,103 Tribune Publishing Company  
10 Boston Globe Boston Massachusetts 230,756 Boston Globe Media Partners  

Àwọn ìwé ìròyìn Amẹ́ríkà tí wọ́n ti wà fún ìgbà pípẹ́ àtúnṣe

Àwọn tó wà ní ìpínlẹ̀ àti àgbègbè kọ̀ọ̀kan àtúnṣe

Àtòjọ Àwọn àtòjọ Ìwé-ìròyìn:

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Newspaper Circulation Volume". Newspaper Association of America. 4 September 2012. Archived from the original on 20 January 2016. Retrieved 20 January 2016. 
  2. "Top 10 U.S. Daily Newspapers". Cision. January 4, 2019. Retrieved 2019-10-26. 
  3. About Us", Press-Republican. Originally published as the Plattsburgh Republican, then became the Press-Republican after a merger on October 5, 1942.
  4. "Prospectus for the Columbus Enquirer, January 1828 | TSLAC". www.tsl.texas.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-01-18.