Àtòjọ àwọn àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ Ní Nigeria

Èyí ni àtòjọ àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ ní Nigeria nípa bí wọ́n ṣe ń powó sí àti owó ìdókowò wọn títí di ọdún 2024, gẹgẹ bí ìfisípò àwọn ilé-iṣẹ́ 500 tó tóbi jùlọ ní Africa tí Jeune Afrique àti African Business. Ó tó ọgbọ́n nínú 500 àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ Ní Africa nípa owó tí wọ́n ń pa wọlé ló wà ní Nigeria.

Nípa iye owó tí wọ́n pa wọlé

àtúnṣe

Àwọn wọ̀nyí ni mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ (láìsí ilé-ìfowópamọ́) nípa iye owó tí wọ́n ń pa wọlé lọ́dún 2022 (pàápàá jùlọ fún ìsúná-owó ọdún 2021).[1]

Ipò Ilé-iṣẹ́ Ẹ̀yà ilé-iṣẹ́ Iye owó tí wọ́n ń pa wọlé ní
(US$ millions)
Èrè tí wọ́n ń jẹ ní
(US$ millions)
1 Nigeria National Petroleum Oil and gas 9,706 1,877
2 Nigeria Liquefied Natural Gas Oil and gas 6,315 ...
3 MTN Nigeria Telecommunications 3,514 536
4 Dangote Cement Cement 2,699 721
5 Nigerian Petroleum Development Oil and gas 2,686 219
6 Flour Mills of Nigeria Agroindustry 2,014 67
7 Airtel Nigeria Telecommunications 1,503 343
8 Nigerian Breweries Agroindustry 890 19
9 Jumia Retail 837 ...
10 Nestle Nigeria Agroindustry 749 102
11 Krystal Digital Network Solutions Infotech 678 21
12 Julius Berger Construction 631 3
13 Nigerian Bottling Company Agroindustry 627 ...
14 Lafarge Africa Cement 602 97
15 Dangote Sugar Refinery Agroindustry 559 78
16 BUA Cement Cement 547 184
17 TotalEnergies Nigeria Oil and gas 534 5
18 Seplat Petroleum Development Oil and gas 498 −80
19 Ardova Plc Oil and gas 474 5
20 11PLC Oil and gas 428 16
21 International Breweries plc Agroindustry 357 −32
22 Conoil Oil and gas 307 ...
23 Honeywell Flour Mill Agroindustry 286 3
24 PZ Cussons Nigeria Consumer goods 216 4
25 UAC of Nigeria Conglomerate 213 11

Nípa iye owó ìdókowò

àtúnṣe

Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ ogún nípa iye owó ìdókowò wọn lọ́dún 2022.[2]

Ipò Ilé-iṣẹ́ Ẹ̀yà ilé-iṣẹ́ Iye owó ìdókowò ní
(US$ millions)
1 Dangote Cement Cement 11,203
2 MTN Nigeria Telecommunications 10,471
3 Airtel Nigeria Telecommunications 6,903
4 BUA Cement Cement 5,759
5 Nestle Nigeria Agroindustry 2,658
6 BUA Foods Agroindustry 2,575
7 Zenith Bank Banking 1,691
8 Guaranty Trust Holding Company PLC Finance 1,585
9 First Bank of Nigeria Banking 1,070
10 Stanbic IBTC Holdings Finance 1,064
11 Lafarge Africa Cement 918
12 Access Holdings Finance 833
13 Nigerian Breweries Agroindustry 890
14 United Bank for Africa Finance 633
15 Ecobank Banking 529
16 Dangote Sugar Refinery Agroindustry 467
17 Union Bank of Nigeria Banking 431
18 Guinness Nigeria Consumer goods 375
19 Okomu Oil Palm Agroindustry 343
20 Presco PLC Agroindustry 320

Ẹ wò yí náà

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Classement 2022 des 500 premières entreprises africaines : le palmarès complet - Jeune Afrique.com". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2024-01-28. 
  2. "Africa’s Top 250 Companies, 2022". African Business (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-09. Retrieved 2024-01-28.