Àtòjọ Orúkọ Àwọn Ọmọ Orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà tí Orírun Wọn Jẹ́ China
Èyí ni àtòjọ Orúkọ Àwọn ènìyàn pàtàkì tí wọ́n jẹ́ ọmọ Amẹ́ríkà ṣùgbọ́n tí orírun wọn jẹ́ China. Àwọn orúkọ wọ̀nyí jẹ́ ti àwọn tí wọ́n kọjá sí Amẹ́ríkà fún ara wọn tàbí àwọn ọmọ Amẹ́ríkà ṣùgbọ́n tí ìran wọn jẹ ti China tí wọ́n sìn tí ṣe nǹkan pàtàkì láwùjọ lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Àwọn oníṣẹ́-ọ̀nà
àtúnṣeÀwọn oníjó
àtúnṣe- Goh Choo San (吴诸珊) – oníjó ballet àti oníjó ẹsẹẹsẹ
- Shen Wei (沈伟) – dancer, oníjó ẹsẹẹsẹ àti ayàwòrán; ọmọlẹ́yìn MacArthur
- Fang-Yi Sheu (許芳宜) – Ògbóǹtarìgì oníjó fún ilé-iṣẹ́ Martha Graham
Gbajúmọ̀ Aránṣọ
àtúnṣe- Malan Breton (马兰·布莱顿) –
- Luly Yang – Aránṣọ
- Angel Chang – Aránṣọ
- Monika Chiang – Aránṣọ
- Wenlan Chia (賈雯蘭) – Aránṣọ
- Doug Chiang (江道格) – Aránṣọ àti eléré tíátà
- David Chu (朱欽騏) – Ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ìránṣọ, Nautica
- Diana Eng – Aránṣọ
- Joe Allen Hong – Aránṣọ fún Neiman Marcus
- Jen Kao – Aránṣọ
- Jonathan Koon – Aránṣọ àti gbajúmọ̀ oníṣòwò
- Derek Lam – Aránṣọ
- Phillip Lim – Aránṣọ
- Peter Mui – Aránṣọ, òṣèré àti olórin
- Mary Ping – Aránṣọ
- Peter Som – Aránṣọ
- Anna Sui (蕭志美) – Aránṣọ
- Vivienne Tam (谭燕玉) – Aránṣọ
- Yeohlee Teng – Aránṣọ
- Alexander Wang (王大仁) – Aránṣọ
- Kaisik Wong – Aránṣọ
- Vera Wang (王薇薇) – Aránṣọ
- Jason Wu (吳季剛) – Aránṣọ
- Joe Zee – Olùdarí iṣẹ́-ọ̀nà fún Magasínnì Elle; ó tún jẹ́ olóòtú ètò aṣọ rírán lórí ètò tẹlifíṣàn tí wọ́n ń pè ní All on the Line
Lítíréṣọ̀
àtúnṣe- Bette Bao Lord (包柏漪) – oǹkọ̀wé àti oǹkọ̀tàn
- Eileen Chang (张爱玲, a.k.a. 张煐) – oǹkọ̀wé
- Kang-i Sun Chang (孫康宜) – oǹkọ̀wé and àti onímọ̀ lítíréṣọ̀
- Lan Samantha Chang – oǹkọ̀wé; olùdarí Iowa Writer's Workshop
- Victoria Chang – Akéwì, oǹkọ̀wé àwọn ọmọdé, àti oǹkaròkọ
- Ted Chiang (姜峯楠) – oǹkọ̀wé ìtàn méèrirí
- Frank Chin (趙健秀) – oǹkọ̀tàn, oǹkọ̀wé eré-oníṣe, àti oǹkàròkọ
- Marilyn Chin (陈美玲) – Akéwì
- Ben Fee (张恨棠/木云) – oǹkọ̀wé àti adarí àwọn òṣìṣẹ́
- David Henry Hwang (黃哲倫) – oǹkọ̀wé eré-oníṣe
- Gish Jen (任璧蓮) – oǹkọ̀wé, oǹkọ̀tàn
- Ha Jin (哈金) – oǹkọ̀tàn, òun ló gbà àmì-ẹ̀yẹ National Book Award fún Waiting
- Maxine Hong Kingston – oǹkọ̀tàn ìwé The Woman Warrior
- R. F. Kuang (匡灵秀) – oǹkọ̀tàn méèrirí ayanilẹ́nu, The Poppy War
- Jean Kwok – oǹkọ̀wé, oǹkọ̀tàn
- Edward Michael Law-Yone – oǹkọ̀wé, oníṣẹ́ ìròyìn; bàbá Wendy Law-Yone
- Wendy Law-Yone – oǹkọ̀wé
- Gus Lee (李健孫) – oǹkọ̀wé
- Carolyn Lei-Lanilau – oǹkọ̀wé
- Yiyun Li (李翊雲) – ẹni tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ PEN/Hemingway lọ́dún 2006
- Ed Lin (林景南) – oǹkọ̀wé, oǹkọ̀wé àkọ́kọ́ tó gba ami-ẹ̀yẹ Asian American Literary Awards ní ẹ̀mẹta [1]
- Tao Lin (林韜) – oǹkọ̀wé
- Eric Liu (劉柏川) – oǹkọ̀wé àti akọ̀wé ọ̀rọ̀-ètò fún Ààre àná Amẹ́ríkà, Bill Clinton[2]
- Malinda Lo – oǹkọ̀wé ìtàn, Ash
- David Wong Louie (雷祖威) – oǹkọ̀wé
- Marie Lu (陸希未) – oǹkọ̀wé
- Adeline Yen Mah (馬嚴君玲) – oǹkọ̀wé àti oníṣẹ́ ìlera
- William Marr (馬為義,非馬) – onímọ̀ ẹ̀rọ, akéwì, aṣògbufọ̀, àti òṣèré
- Anchee Min (閔安琪) – oǹkọ̀wé Red Azalea
- Celeste Ng (伍綺詩) – oǹkọ̀wé, oǹkọ̀tàn
- Lisa See – oǹkọ̀wé
- Sui Sin Far (水仙花) – oǹkọ̀wé àti oníròyìn
- Amy Tan (譚恩美) – oǹkọ̀wé The Joy Luck Club
- Timothy Tau (謝韜) – oǹkọ̀wé, oǹkọ̀tàn, olùdarí eré àti akọ̀wé eré.
- Jade Snow Wong (黃玉雪) – oǹkọ̀wé
- Shawn Wong – oǹkọ̀tàn ìwé Homebase, American Knees; oǹkọ̀wé; ọ̀jọ̀gbọ́n
- Timothy C. Wong (黃宗泰) – onímọ̀ nípa China, aṣògbufọ̀, àti onímọ̀ ìlànà lítíréṣọ̀
- Xu Xi (許素細) – oǹkọ̀wé èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ó ń gbé ní Hong Kong
- Geling Yan (严歌苓) – oǹkọ̀tàn àti oǹkọ̀wé eré
- Gene Luen Yang (楊謹倫) – oǹyàwòrán ìwé ìtàn, tí ìwé rẹ̀, American Born Chinese jẹ́ ìwé ìtàn tí wọ́n yàn án fún ami-ẹ̀yẹ àwòrán ìwé àkọ́kọ́ fún National Book Award
- Laurence Yep (叶祥添) – ó gba ami-ẹ̀yẹ lẹ́ẹ̀mejì fún ìwé rẹ̀, Newbery Honor
- Connie Young Yu – oǹkọ̀wé, asọ̀tàn, olùkọ́ ilé-ìwé gíga, òun ló sìn gba ami-ẹ̀yẹ gbajúmọ̀ obìnrin tó dára jù lọ lọ́dún 2016 ní California Senate District 13
- Judy Yung – oǹkọ̀wé
Tíátà
àtúnṣe- Ping Chong (張家平) – olùdarí eré tíátà ìgbàlódé
- Dan Kwong – oǹkọ̀wé eré-oníṣe
- BD Wong – ó gba ami-ẹ̀yẹ Tony Award-winning, M Butterfly, Law & Order: Special Victims Unit
Àwọn oníṣẹ́-ọ̀nà àfojúrí
àtúnṣe- Ernie Chan – oǹkọ̀wé adẹ́rìnínpòṣónú Marvel Comics àti DC Comics.
- Alexander Chen – eléré fún US Olympic Team
- Ching Ho Cheng – eléré
- Alan Chin – eléré
- Mel Chin – eléré
- Cai Guo-Qiang (蔡國強) – eléré
- Han Hsiang-ning (韓湘寧) – eléré
- James Wong Howe (黃宗霑) – ẹni tí wọ́n yàn fún ami-ẹ̀yẹ mẹ́wàá fún Academy Awards for cinematography,ó sìn gbà á lẹ́ẹ̀mejì lọ́dún 1955 àti 1963
- Juliette Leong – oṣèré ọmọdé ọlọ́gbọ́n child prodigy àti alálàyé
- Maya Lin (林瓔) – ayàwòrán-ẹ̀kọ́lé (Vietnam Veterans Memorial)
- Reagan Louie – Ayàwòrán ọmọ Amẹ́ríkà
- Seong Moy – akùnle àti olóùntẹ̀
- I. M. Pei (貝聿銘) – Ayàwòrán ẹ̀kọ́lé, tí ó ya àwòrán ẹ̀kọ́lé ilé Louvre Pyramid
- Mimi So – Ayàwòrán ohun ẹ̀ṣọ́
- May Sun – eléré
- Fan Tchunpi – Ayàwòrán, afíngba
- Frank Wong – eléré dioramist
- Tyrus Wong (黃齊耀) – eléré
- Frank Wu – onímọ̀ eré ìtàn méèrirí
- Xu Bing – eléré
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Streetside Chat with Author Ed Lin, TaiwaneseAmerican.org, http://taiwaneseamerican.org/ta/2012/05/24/streetside-chat-with-author-ed-lin/
- ↑ Tewari, Nita; Alvarez, Alvin (2008-09-26). Asian American psychology: current perspectives. CRC Press. pp. 117–. ISBN 978-0-8058-6008-5. https://books.google.com/books?id=m8qgAi0LVj8C&pg=PA117. Retrieved 6 March 2011.