Àwọn ènìyàn Kalanga
Kalanga tàbí Bakalanga jẹ́ àwọn ènìyàn kan tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà Bantu tí ó ń gbé ní Matebeleland ní Zimbabwe, apá àríwá ìlà oòrùn Botswana àti agbègbè Limpopo ní orílẹ̀ èdè South Africa. Wọ́n tan mọ́ àwọn ọmọ Nambya, Karanga, Bapedi àti Venda.
Kalanga group.jpg | ||||||
Àpapọ̀ iye oníbùgbé | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
1.6 million | ||||||
Regions with significant populations | ||||||
| ||||||
Èdè | ||||||
TjiKalanga, Shona languages ,Xitsonga,TshiVenda language | ||||||
Ẹ̀sìn | ||||||
Ẹ̀yà abínibí bíbátan | ||||||
Shona, and other Southern Bantu peoples |
Àwọn ọmọ BaKalanga wá láti ìran Leopard Kopje’s. Ìtàn wọn fihàn pé àwọn ni ó dá ìjọba Mapungubwe kalẹ̀ ní gúúsù Áfríkà. Àwọn ènìyàn BaKalanga ti Botswana jẹ́heya ìkejì tíró eóbi jùlọ àti èdè kejì tí wọ́n ń sọ jùlọ ní orílẹ̀ èdè náà.yÈdèhe TjiKalangtiof Zimbabwni èdè kẹea tí wọ́n ń sọ jùlọ ní orílẹ̀ èdè náà, àwọ́n oníròyìn kọ̀kan ní orílẹ̀ èdè náà tún ń lò ó láti fi ka ìròyìn
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Lewis, M. Paul (2009). "Kalanga 'The cultural people'". Ethnologue. SIL International. Retrieved 25 October 2012.