Àwọn ṣòro igun aago
Àwọn iṣòro igun aago jẹ́ irú ìṣòro ìṣirò tí ó ní ṣe pẹ̀lú wíwá àwọn igun láàrín àwọn ọwọ́ aago àfọwọ́ṣè.
Ìṣòro ìṣirò
àtúnṣeÀwọn ṣòro igun aago ṣe àkàwé àwọn ìwọ̀n méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: igun àti àkókò. Wọ́n ma a ń wọn igun pèlú degree lati ààmì iye méjìlá sí apá ọ̀tún. Àkókò yìí dá lórí aago wákàtí méjìlá.
Ọ̀nà tí à ń gbà sọ àwọn ìṣòro yìí di pẹ̀tẹ́lẹ̀ ni ìyípadà igun ní degree fún ìṣẹ́jú kan. Ọwọ́ wákàtí fún déédé wákàtí méjìlá aago àfọwọ́ṣe ń yípo 360° ní àwọn wákàtí méjìlá (ìṣẹ́jú 720) tàbí 0.5° fún ìṣẹ́jú kan. Ìṣẹ́jú ọwọ́ yí má a ń yípo nípasẹ̀ 360° ní àwọn ìṣẹ́jú 60 tàbí 6° fún ìṣẹ́jú kan.[1]
Ìbádọ́gba fún igun ti ọwọ́ wákàtí
àtúnṣení ibi tí:
- θ jẹ́ igun àwọn degree tí ìwọn ọwọ́ ìwọ̀n ìyípo apá ọ̀tún láti méjìlá
- MΣ jẹ́ àwọn ìṣẹ́jú tí ó kọjá aago méjìlá .
- H jẹ́ wákàtí yẹn .
- M jẹ́ àwọn ìṣẹ́jú tí ó kọjá wákàtí yẹn.
Ìbádọ́gba fún igun ti ọwọ́ ìṣẹ́jú
àtúnṣe- θ jẹ́ igun àwọn degree tí ìwọn ọwọ́ ìwọ̀n ìyípo apá ọ̀tún láti ipò aago méjìlá.
- M jẹ́ ìṣẹ́jú yẹn.
Àpẹẹrẹ
àtúnṣeÀkókò yẹn ni 5:24. Igun yẹn ní àwọn degree ti ọwọ́ wákàtí ni:
Igun yẹn mí àwọn degree ti ọwọ́ ìṣẹ́jú ni:
Ìbádọ́gba fún igun ti láàrín àwọn ọwọ́ yẹn
àtúnṣeA lè rí igun tí ó wà láàrín àwọn ọwọ́ yẹn nípasẹ̀ lílo àgbékalẹ̀ yìí:
ní ibi tí
- H ti jẹ̣́ wákàtí
- M ti jẹ̣́ ìṣẹ́jú
Tí igun yẹn bá 180 degree, kí a yọọ́ kúrò ní 360 degrees
Àpẹẹrẹ
àtúnṣeÀkókò yẹn jẹ́ 2:20.
Ní ìgbà tí ọwọ́ wákàtí àti ìṣẹ́jú aago bá wà lórí ara wọn?
àtúnṣeỌwọ́ wákàtí àti ìṣẹ́jú ma ń wà lórí ara wọ́n nígbà tí igun wọn bá jẹ́ bákan náà.
H jẹ́ odidi láàárín 0–11. Èyí fún wa ní ìlọ́po: 0:00, 1:05.45, 2:10.90, 3:16.36, 4:21.81, 5:27.27. 6:32.72, 7:38.18, 8:43.63, 9:49.09, 10:54.54, àti 12:00. (ìṣẹ́jú 0.45 jẹ́ déédé aáyá 27.27 .)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣeÀwọn ìjápọ̀ látìta
àtúnṣe- http://www.delphiforfun.org/Programs/clock_angle.htm Archived 2010-06-15 at the Wayback Machine.
- http://www.ldlewis.com/hospital_clock/ - extensive clock angle analysis
- http://www.jimloy.com/puzz/clock1.htm Archived 2010-06-08 at the Wayback Machine.