Àwọn eré-ìdárayá ìdíje Òlímpíkì
Àwọn eré-ìdárayá ìdíje Òlíḿpíkì ni awony eré-ìdárayá tí wọ́n máa ń díje fún nínú Ìdíje Òlíḿpíkì Ìgbà ẹ̀rùn ati Ìgbà òjò. Olimpiki Igba Oru 2012 ni ere-idaraya 26, be sini afikun yio ba iye awon ere-idaraya fun Olimpiki Igba Oru 2016. Olimpiki Igba Otutu 2014 ni ere-idaraya meje.[1]
The number and kinds of events may change slightly from one Olympiad to another. Each Olympic sport is represented by an international governing body, namely an International Federation (IF).[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Olympic Sports". International Olympic Committee. Retrieved 2010-03-13.
- ↑ "Olympic Sports, Disciplines & Events". HickokSports.com. 2005-02-04. Archived from the original on 2007-04-18. Retrieved 2007-03-18.