Àyinla Omowura

Olorin omo orile-ede Naijiria

.[1][2][3]

Wàídì Àyìnlá Yusuf Gogbo lòwò tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Àyìnlá ọmọwúrà (1933- 6 May 1980) ó jẹ́ olórin àpàlà orílé-èdè Nàìjíríà. Tí wọn bí ní Itoko, Abé̩òkúta ní ọdún 1933.

Alhaji

Ayinla Omowura

Background information
Birth name Waidi Ayinla Yusuf Gbogbolowo
Also known as Ayinla Omowura

Hadji (Alhaji) Consulate Egunmogaji of Egbaland Anigilaje

Born 1933

Itoko, Abeokuta

Died 6 May 1980 (aged 46–47)

Bar in Ago-Ika, Abeokuta

Genres Apala
Occupation(s) Musician
Years active 1970–1980
Labels EMI Records

Ìtàn ìgbésí ayé rè̩

àtúnṣe

Ọmọwúrà jẹ́ ọmọ bíbí inú Yusuf Gbogbolówó, alágbèdẹ àti Wúràmọ́tù Morẹ́nikẹ́. Ó jẹ́ ẹni tí kò ní ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìgbàlódé.

Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní bá Bàbá rẹ̀ ṣiṣẹ́ àgbẹ̀dẹ ṣùgbọ́n tí ó padà kúrò tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣe oríṣiríṣi isẹ́ bí awakọ̀, alàpatà, káfíńtà, ọmọ lẹ́yìn ọkọ̀. Adewole Alao Oniluola wá ṣàwárí rẹ̀, tí ó padà jẹ́ olórí onílù rẹ̀ àti ṣíṣe elégbè ní Ọlalọmi, nínu ṣíṣe eré àpàlà.


Ikú rẹ̀

Àyìnlá kú ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Karù-ún, ọdún 1980 lé̩ni ọmọ ọdún Mé̩tàdínláàdó̩ta (47), látàrí aáwọ̀ ránpẹ́ tó wáyé láàrín òun àti ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀, tí tọ̀hún si ṣe bẹ́ẹ̀ fọ́ ife ìmumi aláwo mọ lórí tí ó si gbà bẹ̀ jé̩ ìpe Olódùmarè.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe