Ájálù to ṣẹ̀lẹ nipa Ìfómipamọ ti Gusau
Ìfómipamọ ti Gusau ni ìfomipamọ to wa ni ódó sokoto ni apa oke lati Gusau, ólu ipinlẹ Zamfara ni órilẹ ede Naijiria. Ìfómipamọ naa pin omi fun awọn ilù ati àgbègbè ipinlẹ naa. Ni ọdun 2006, Ìfómipamọ naa ṣubù eyi lo fa iku awọn èniyan ógóji ati iparun ile ti ẹẹdẹ̀gbẹta[1].
Gbigbẹ Ìfómipamọ Gusau ni ọdun 2001
àtúnṣeÌfómipamọ naa kuna lati pèsè ómi fun awọn àrà ilu nigba ọgbẹlẹ. Ni óṣu January, ọdun 2001, Gomina Ipinlẹ Zamfara, Ahmed Sani Yerima ri minister lori eto omi Mohammed Bello Kaliel lori gbigbẹ ìfómipamọ naa to si damọran ki wọn mu ómi lati Ìfómipamọ ti Bakolori lọsi ti Gusau[2].
Ìṣubu Ifómipamọ Gusau ni ọdun 2006
àtúnṣeÁjàlu ṣẹlẹ̀ ni ọjọ Ábàmẹta, ọjọ ọgbọn, óṣu September, ọdun 2006 nibi ti ifòmipamọ Gusau ti ṣubu lẹyin ọpọlọpọ ìkun ómi to lagbara. Ógòji eniyan ku ti ẹẹdẹgbẹta ilè si paarun eyi lo sọ awọn eniyan ẹ̀ẹgbẹrun nu[3].
Àjalu yii ṣẹ̀lẹ̀ nipa ójó to lagbara rọ ni aágbègbè naa ni ọjọ mèji tẹle ra wọn. Ọpọlọpọ èrè ókó lo bajẹ̀ ati ọpọlọpọ ẹran isin lo lu latari ìṣẹ̀lẹ naa[4].
Áfara to wa ni apa ariwa ipinlẹ Zamfara naa tun ṣubu yatọsi iṣẹ̀lẹ̀ ti Ìfómipamọ[5]. Awọn èniyan ẹẹdẹgbẹrin ni wọn gbè ni ilè iwè àgbègbè Birnin Ruwa nitori ìṣẹlẹ naa[6]. Awọn kanga to wa fun mimu ni ómi ìkun omi bajẹ̀ to si di eyi ti ko ṣè mumọ fun awọn èniyan[7].
Gẹ̀gẹbi iwadi ajọ to mojuto ọrọ omi ni ipinlẹ Zamfara, ìṣẹlẹ yii waye ni to ri pè ẹrọ ti Sluice gates kuna lati ṣiṣẹ̀ eyi ki ómi pọju fun ìfómipamọ naa[8][9].
Lẹ̀yin íṣubu ifómipamọ naa, awọn ólugbè agbegbe yii bẹrẹ̀ si ni mu ómi ti ṣiṣan eyi lo mu ki awọn ti oun ta omi fi alekun ba iye ti wòn ta ómi wọn[10].
Awọn ìtọkasi
àtúnṣe- ↑ "Dam collapse floods town". News24. 2006-10-01. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "THISDAYonline". thisdayonline.com. 2001-01-12. Archived from the original on 2004-12-06. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Nigeria: Collapsed dam sweeps away 500 houses - Nigeria". ReliefWeb. 2006-10-02. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Scores killed as Nigeria dam bursts". The Mail & Guardian. 2006-10-01. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ Royal, David O (2020-09-17). "Flood claims one life, destroys over 900 houses in Zamfara — NEMA". Vanguard News. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Nigeria Dam Collapse Destroys Hundreds of Homes". VOA. 2009-10-31. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Victims of Dam Collapse in Nigeria Get Help". Fox News. 2015-01-13. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Burst dam destroys Nigeria homes". BBC NEWS. 2006-10-01. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ "Nigeria: Officials fear water crisis for thousands - Nigeria". ReliefWeb. 2006-10-06. Retrieved 2023-09-17.
- ↑ Nwannah, Ifeanyi (2023-05-16). "Acute water shortage in Gusau: Hold Zamfara govt responsible - Water Board". Daily Post Nigeria. Retrieved 2023-09-17.