Áljẹ́brà onígbọrọ

(Àtúnjúwe láti Áljẹ́brà alátẹ̀lé)

Aljebra gbigboro (linear algebra) je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon atokaona (vector), aaye atokaona (vector space), maapu gbigboro (linear map) ati awon ona-eto idogba gbigboro (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi aljebra alatele wulo lopolopo ninu aljebra afoyemo ati agbeyewo alabase (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon sayensi aladabaye ati sayensi awujo nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).

A line passing through the origin (blue, thick) in R3 is a linear subspace, a common object of study in linear algebra.

Ìtàn Áljẹ́brà gbigboro

àtúnṣe

Itan aljebra ayeodeoni bere ni arin odun 1843 ati 1844. Ni odun 1843, William Rowan Hamilton (eni ti o koko soro nipa atokaona) se awari quaternions. Ni odun 1844, Hermann Grassmann ko iwe ni ede Germani pelu akole Die lineale Ausdehnungslehre. Arthur Cayley mu apotinomba (matrix) wa ni odun 1857. Ilana Cramer to n fihan wa bi a se le s'ojutu awon idogba iseyato abo (partial differential equation) lo so aljebra alatele di eko ti a n ko ni awon ile-eko giga. Fun apere, E.T. Copson ko pe:

Ni odun 1922 ti mo di oluko kekere ni ile-eko giga Edinburgh, o yamilenu lati ri pe ilanaeto eko yato si ti ile-eko giga Oxford. Eka bi isodiodidi Lebesgue (Lebesgue integration), ero apotinomba (matrix theory), agbeyewo aminomba (numerical analysis), alawonile Riemannian (Riemannian geometry), lori awon eyi ti n ko mo nkankan nipa won.... E.T. Copson, Oro Isaju si Idogba Iseyato Abo, 1973