Átẹ́gùn Ooru
Átẹ̀gun Óóru jẹ óóru to làgbàrà nigba asiko óju ọjọ to gbónà[1][2]. ọriniinitutu giga maa nwa pẹ̀lu Átẹ̀gun Óóru. Èyi maa nṣẹlẹ ni órilẹ èdè tí o ni ójù ọjọ tó fara pẹ ókun[3].
Ìwọn Átẹgun óórù jẹ ìbàtàn fun ọju ọjọ àgbègbè ati deede otutu fun igba. Óóru to wa lati àgbègbè awọ̀n eniyan to wa ni ójù ọjọ gbigbóna jẹ Átẹgun óórù fun awọn ti oun gbè ni agbègbè to tutu. Èyi maa ṣẹlẹ ti gbìgbona otutu ba yatọ̀ si apẹrẹ ójù ọjọ fun àgbègbè naa[4]. Átẹgun óórù wọpọ to dẹ tun làgbàrà lori ilẹ kàkirì àgbègbè lati ọdun 1950s latari Àyipadà ójù ọjọ[5].
Átẹgun óórù to lagbara maa njẹki ohun ọgbin bajẹ, Ooru yi jẹ a lèkun fun iṣẹlẹ iná ninu igbó ni awujọ ọgbẹ̀lẹẹ[6][7]. Eyi maa jasi àyipada inà ijọba nitori imulètutu ti awọn èniyan ló.
Átẹgun óórù jẹ ójù ọjọ to làgbàrà eyi lo ma fa ailèrà fún awọn èniyan nitóri óóru ati óórun maa nbóri awọn ẹ̀yàeto itutu ara eniyan[8]. Ó ṣèṣè latiri Átẹgun óórù pẹ̀lù awọn ìrìnṣẹ Àfojúsùn ojú ọjọ.
Ipa atẹ́gùn ooru ninu ilera ènìyàn
àtúnṣeÀyipada òju ọjọ jẹ alekun óórun, èyí jẹ àkóbá fun awọn èniyan bí aisun, èwu ninu oyun àti aisan kíndìnrín[9]. Èwu inu óyun maa njasi bibi ọmọ ti kógbó ati ibimọ aitọjọ. Átẹgun óórù maa njasi Aisan kidinrin to lagbàrà[10].
Awọn ónimọ ilèra ki lọ pè óóru ro lagbara lè jasi iku aisan ọkan, ọpọlọpọ, mimi ato óriṣiriṣi iku[11]. Iku nitori óóru ti ju ọmọ ọ̀dun àrún dín ní àádọ́rin lọ. Eyi lọ jasi iku awọn èniyan ọ̀kẹ́ mẹ̀tàdínlógún ni ọ̀dun 2019[12].
Awọn ara ilu Europe ti ounka ọna ọ̀kẹ́ mẹ̀ta àbọ̀ ku nitori Átẹgun óórù Europe to ṣẹlẹ ni ọdun 2003[13]. Awọn ènìyàn ẹgbẹrun mèji lo ku nitori isẹ̀lẹ Átẹgun óórù to lagbara ni Karachi, Pakistan tó waye ni óṣu June, ọdun 2015[14].
Ikù óóru wọpọ ninu ilè papa julọ ni ọ̀dọ awọn àrugbó nitori pe wọn maa ndagbè. Óóru maa njẹki ipà idọti afẹfẹ pọ̀si ni agbègbè to ti dagbasókè. Eyi jẹ ki iku óóru pọ̀ nigba Átẹgun óórù[15].
Óóru yi fa wahala sinu àrà èyi lo maa nkóba iṣẹ. Óóru tun maa da ija lẹ laarin awọn èniyan ni awujọ to si maa njasi pipa èniyan ati fifi ipa bani làjọṣèpọ. Nigbà miran óórun maa nfa ija àbẹlè eyi jẹ ipalara fun ilèrà awọ̀n èniyan to wa ni àgbègbè[16].
Awọn Ìtọkasi
àtúnṣe- ↑ "CID Impacts September 2003". IRI – International Research Institute for Climate and Society. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ "Definition of HEAT WAVE". Merriam-Webster. 2023-09-28. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Meehl, Gerald A.; Tebaldi, Claudia (2004-08-13). "More Intense, More Frequent, and Longer Lasting Heat Waves in the 21st Century". Science (American Association for the Advancement of Science (AAAS)) 305 (5686): 994–997. doi:10.1126/science.1098704. ISSN 0036-8075.
- ↑ Robinson, Peter J. (2001-04-01). "On the Definition of a Heat Wave". Journal of Applied Meteorology and Climatology (American Meteorological Society) 40 (4): 762–775. doi:10.1175/1520-0450(2001)040<0762:OTDOAH>2.0.CO;2. ISSN 1520-0450. https://journals.ametsoc.org/view/journals/apme/40/4/1520-0450_2001_040_0762_otdoah_2.0.co_2.xml. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Thompson, Andrea (2023-07-25). "This Summer’s Record-Breaking Heat Waves Would Not Have Happened without Climate Change". Scientific American. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ García-León, David; Casanueva, Ana; Standardi, Gabriele; Burgstall, Annkatrin; Flouris, Andreas D.; Nybo, Lars (2021-10-04). "Current and projected regional economic impacts of heatwaves in Europe". Nature Communications (Springer Science and Business Media LLC) 12 (1). doi:10.1038/s41467-021-26050-z. ISSN 2041-1723.
- ↑ Clarke, Ben; Otto, Friederike; Stuart-Smith, Rupert; Harrington, Luke (2022-06-28). "Extreme weather impacts of climate change: an attribution perspective". Environmental Research: Climate (IOP Publishing) 1 (1): 012001. doi:10.1088/2752-5295/ac6e7d. ISSN 2752-5295.
- ↑ Bottollier-Depois, Amélie (2022-06-15). "Deadly heatwaves threaten economies too". Phys.org. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Shih, Gerry (2023-01-06). "The world’s torrid future is etched in the crippled kidneys of Nepali workers". Washington Post. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Glaser, Jason; Lemery, Jay; Rajagopalan, Balaji; Diaz, Henry F.; García-Trabanino, Ramón; Taduri, Gangadhar; Madero, Magdalena; Amarasinghe, Mala et al. (2016-05-05). "Climate Change and the Emergent Epidemic of CKD from Heat Stress in Rural Communities: The Case for Heat Stress Nephropathy". Clinical Journal of the American Society of Nephrology (Ovid Technologies (Wolters Kluwer Health)) 11 (8): 1472–1483. doi:10.2215/cjn.13841215. ISSN 1555-9041.
- ↑ "Heat Illness: MedlinePlus". National Library of Medicine. 2020-12-16. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Romanello, Marina; McGushin, Alice; Di Napoli, Claudia; Drummond, Paul; Hughes, Nick; Jamart, Louis; Kennard, Harry; Lampard, Pete et al. (2021). "The 2021 report of the Lancet Countdown on health and climate change: code red for a healthy future". The Lancet (Elsevier BV) 398 (10311): 1619–1662. doi:10.1016/s0140-6736(21)01787-6. ISSN 0140-6736.
- ↑ Robine, Jean-Marie; Cheung, Siu Lan K.; Le Roy, Sophie; Van Oyen, Herman; Griffiths, Clare; Michel, Jean-Pierre; Herrmann, François Richard (2008). "Death toll exceeded 70,000 in Europe during the summer of 2003". Comptes Rendus Biologies (Elsevier BV) 331 (2): 171–178. doi:10.1016/j.crvi.2007.12.001. ISSN 1631-0691.
- ↑ "Heat Wave Death Toll Rises to 2,000 in Pakistan’s Financial Hub". Bloomberg.com. 2015-06-24. Retrieved 2023-09-29.
- ↑ Diem, Jeremy E.; Stauber, Christine E.; Rothenberg, Richard (2017-05-16). "Heat in the southeastern United States: Characteristics, trends, and potential health impact". PLOS ONE (Public Library of Science (PLoS)) 12 (5): e0177937. doi:10.1371/journal.pone.0177937. ISSN 1932-6203.
- ↑ Burke, M.; Hsiang, S.; Miguel, E. (2014). "Climate and Conflict". SRPN: Sustainable Development (Topic). https://www.semanticscholar.org/paper/Climate-and-Conflict-Burke-Hsiang/c8a494fd49af3e3b5a0988f438ac7dc6f05ed89f. Retrieved 2023-09-29.