Èdè Igbìrà tàbí Ebira tàbí Egbira jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Kwárà àti Ẹdó àti Násáráwá). Èdè Igbìrà Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Naìjírìà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan. Wọn wà ní àgbègbè Èbìrà ní ìpínlè Kogi, Kwara, Edo, àti béè béè lo. Àwon èka èdè tí ó wà ní abẹ́ rẹ̀ ni Okene (Hima, Ihima) ìgbàrà (Etunno) Èbìrà ní ìsupò èka èdè, wón ń lò ó ní ilé ìwé.

Ebira
Sísọ níNàìjíríà
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1989
AgbègbèÌpínlẹ̀ Kwárà, Ìpínlẹ̀ Ẹdó, Ìpínlẹ̀ Násáráwá
Ẹ̀yàÀwọn Ebira
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀1,000,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3igb

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe