Èdè kan ni eléyìí lára àwọn èdè tí a ń pè ní Abkhazo-Adyghian tí àwọn wọ̀nyí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àkójọpọ̀ èdè tí a ń pè ní caucasian (Kọ̀kọ́síànù). Àwọn tí ó ń sọ Abkhaz tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún ènìyàn ní ìpínlẹ̀ tí a ń pè ní Abkhaz ní Georgia. Ó wà lára àwọn èdè ti ìjọba ń lò níbẹ̀. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní apá kan ilẹ̀ Tọ́kì (Turkey).

Abkhaz
Аҧсуа бызшәа; аҧсшәа
Sísọ ní

Turkey, Russia, Georgia, Jordan, Syria, Iraq

Abkhazia (Recognized as independent by Russia, Nauru, Nicaragua, and Venezuela)
Agbègbè Caucasia
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 125 000
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọ Abkhaz alphabet
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́ Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 ab
ISO 639-2 abk
ISO 639-3 abk

àkọtọ́ Cyrillic (Sìríhìkì) ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.


ItokasiÀtúnṣe