Èdè Ainu Èdè kan tí ó dá dúró ní òun nìkan ni èdè yìí. A kò mọ iye ẹni tí ó ń sọ ọ ṣùgbọ́n ètò ìkànìyàn ọdún 1996 so pe márùndínlógún ni wọ́n. Hokkaido, Japan àti ní Sakhalin àti Erékùsù Kuril. Ní ìbẹ̀rẹ̀ sẹ́ńtúrì ogún, púpọ̀ núnú àwọn ohun tí ó se pàtàkì nínú èdè àti àṣa Ainu ni Jepaníìsì ti gba ipò wọn

Ainu
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
Hokkaidō; formerly southern and central Sakhalin, the Kuril Islands, and perhaps the tip of the Kamchatka Peninsula and theTōhoku Region of Honshū
Ìyàsọ́tọ̀:A primary language family
Àwọn ìpín-abẹ́:
Sakhalin Ainu
Kuril Ainu