Olùkùmi (tàbí Ulukwumi, Ulukhwumi) jẹ́ èdè irú YorùbáNàìjíríà (ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà).[1]

Olùkùmi
Sísọ níNàìjíríà
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1992
AgbègbèÌpínlẹ̀ Dẹ́ltà
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀10,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3ulb
Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Olùkùmi Èdè Yorùbá Èdè Òwé Èdè Igala
hand ọwọ́ ọwọ́ ọwọ́ ọwọ́
yam usu isu usu/isu uchu
body ara ara ọra ọla
child ọma ọmọ ọmọ ọma
friend oluku ọ̀rẹ́ olúku ónùkú
woman obìnrin obìnrin obùnrin ọ́bùlẹ
father ba bàbá baba àtá
person ẹnẹ ẹni ọni ọ́nẹ̀
fire una iná uná úná
word ọ̀fọ̀ ọ̀rọ̀ ọ̀rọ̀ ọ̀là
heart ẹdọ ọkàn ẹ̀kẹ̀dọ̀ ẹdọ
pot usa ìsà usà ùchà
cow ẹla malu ẹlá ẹla
old person arigbo arúgbo arígbó ògìjo
rat eku eku eku íkélékwu
carry gbe gbé gbe
eat zẹ jẹ jẹ jẹ
colanut obì obì obì obì
water omi omi omi omi
urine ìtọ́ ìtọ́ ìtọ́ ìtọ́
cotton owu owu owu owu
stone òkúta òkúta òkúta òkúta

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Arokoyo, Bolanle Elizabeth. 2012. A Comparative Phonology of the Olùkùmi, Igala, Owe and Yoruba Languages. Paper presented for the International Congress "Towards Proto-Niger-Congo: Comparison and Reconstruction", Paris, 18-21 September, 2012. 10pp.