Ètè ni èyà ara tí ó jẹ́ àbáwọlé sí ẹnu ọmọnìyàn àti Ẹranko tí fara hàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó mú kí orí ó pé níye. Ètè tún jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó ma ń lọ sókè, sílẹ̀, sọ́tùn ún àti ósì yálṣ nígbà tí a bá ń jẹun, mumi, tàbí tàbí sọ̀rọ̀.[1]

Àwọn Ìtọ́ka síÀtúnṣe

  1. "Lips". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-04-19.