Édẹ́nì ti ihà Ìlà Oòrùn
Édẹ́nì ti ihà Ìlà Oòrùn (bí a ti n kọ ní èdè Japanisi: 東のエデン, àti ní èdè Hepburn: Higashi no Eden) jẹ́ eré ìgbà-dé-gbà orí ẹ̀rọ mohunmaworan ti o da lori ẹranko, ti a kọ́kọ́ ṣe afihan rẹ̀ lorí ẹ̀rọ mohunmaworan Fuji ni ọjọ́ kẹsan oṣù kẹrin ọdún 2009 ni àkókò ti àwọn oluworan pọ julọ. Oludasilẹ, oludari ati onko ere naa ni Kenji Kamiyama, o si ṣe àfihàn àwọn onsere ti Chika Umino ṣẹda àti àwọn idaraya ti ilé iṣẹ́ Production I.G. gbé kalẹ̀. A gbe ere yii kale lori itan ti Kamiyama ko ni igba kan ri, oun si ni ojulowo ere akoko ti ile ise ẹ̀rọ mohunmaworanit noitaminA gbé jáde.[1]=Àwon ìtokasí==
- ↑ "Higashi no Eden". MyAnimeList.net. 2010-11-22. Retrieved 2019-08-04.