Émile Durkheim (April 15, 1858 – November 15, 1917) je onimo awujo omo ile Fransi ti o ko ipa pataki ninu imo awujo ati imo eda. O ko opolopo iwe lori eko, iwa odaran, esin igbaemi araeni ati lori opolopo eka awujo.

Émile Durkheim
Ìbí(1858-04-15)Oṣù Kẹrin 15, 1858
Épinal, France
AláìsíNovember 15, 1917(1917-11-15) (ọmọ ọdún 59)
Paris, FranceItokasi àtúnṣe