Étienne Goyémidé (22 Oṣù Kínní Ọdún 1942–17 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1997) jẹ́ ònkọ̀wé àti ònkọ̀tàn eré ọmọ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún kíkọ àwọn ìwé-ìtàn tí àkọ́lé wọ́n jẹ́ Le silence de la forêt àti Dernier Survivant de la caravane.[2]

Étienne Goyémidé
Ọjọ́ìbíÉtienne Goyémidé
(1942-01-22)22 Oṣù Kínní 1942
Ippy, Central African Republic
Aláìsí17 March 1997(1997-03-17) (ọmọ ọdún 55)
Orílẹ̀-èdèCentral African
Iṣẹ́Writer, playwright, poet
Ìgbà iṣẹ́1976–1997

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Etienne Goyémidé: République centrafricaine". Afri Cultures. Retrieved 21 October 2020. 
  2. "Étienne Goyémidé (b. 1942)". Oxford Reference. Retrieved 21 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe