Étienne Mourrut (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kejìlá ọdún 1939 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 2014) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Faransé Ó ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ Ilé -Ìgbìmọ̀ Aṣòfin ní orílè-èdè Faransé.[1]

Étienne Mourrut
Ome Egbe Ile-Igbimo Asofin
In office
17 June 2002 – 17 June 2012
AsíwájúAlain Fabre-Pujol
Arọ́pòGilbert Collard
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kejìlá 1939 (1939-12-04) (ọmọ ọdún 84)
Le Grau-du-Roi, France
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnion for a Popular Movement
(Àwọn) olólùfẹ́Michèle Mourrut



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Étienne Mourrut". FamousFix.com. 1939-12-04. Retrieved 2019-12-04.