Ìṣe Òfin àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú 1964

Ìṣe Àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ti ọdún 1964 je ofin pataki ni orile-ede Amerika ti o fi ofin de iwa eleyameya n'ile eko, n'igboro ati l'enu ise. A da sile lati fi se ranlowo fun awon Ọmọ Afrika Amerika.

First page of the Civil Rights Act of 1964Itokasi àtúnṣe