Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan jẹ́ ọ̀kan lára Ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà tí a tún mọ̀ sí Kofid-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé. Ohun tí ó ń ṣokùnfà àìsàn yí ni àrùn ọ̀fun, àyà, ati imú tí wọ́n ń pè ní [1]
Ìbúrẹ́kẹ́ Àjàkálẹ̀ Àrùn Kofid-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan | |
---|---|
Àrùn | Kofid-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Sudan |
Index case | Khartoum |
Arrival date | 13 March 2020 (4 years, 8 months, 2 weeks and 1 day) |
Active cases | 4,179 (as of 14 July) |
Bí àrùn Kòrónà ṣe wọ orílẹ̀-èdè Sudan
àtúnṣeÀjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pw ní ìgboro Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Wón tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ siwájú si wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, oun ni ó ń fa ìfúnpinpin ní ní inú káà ọ̀fun ati àyà, tí ó sì ma ń fa kàtá tàbí kí []ènìyàn]] ó ma wú ikọ́ tàbí sín léra léra. [2][3] Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003.[4][5] Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó.ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ. [6][4]
Àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan tí ó ṣẹlẹ̀
àtúnṣeOṣù Kẹ́ta ọdún 2020
àtúnṣeNí ọjọ́ Kẹtàlá oṣù kẹ́tà, orílẹ̀-èdè Sudan ní akọsílẹ̀ Kòrónà akọ́kọ́ ní agbègbè Khartoum. Aláìsàn náà ti kọ́kọ́ndé orílẹ̀-èdè United Arab Emirates ṣáájú kí ó ṣe aláìsí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹ́ta ọdún 2020.[7] Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yí, orílẹ̀-èdè Sudan fopin sí fífún àwọn èró láti ilé òkèrè ìwé ìrìnà ìkíni sí àwọn orílẹ̀-èdè tí àrùn náà nti pọ̀ jùlọ, tí ó fi mọ́ orílẹ̀-èdè Italy àti orílẹ̀-èdè Ijíbítì tí ó jẹ́ alámùúké tì wọn nítorí ìbérù àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà. [8]
Oṣù Karùún ọdún 2020
àtúnṣeNígbà tí ó di ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù Karùún, àwọn ìròyìn ikú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn látàrí Ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà, dá ìbẹ̀rù-bojo sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Sudan, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìgbésẹ̀ ayẹ̀wò àrùn aṣekúpani náà mẹ́hẹ. [9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Federal Ministry Of Health". Federal Ministry Of Health. 3 April 2020.
- ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Sudan reports first coronavirus case". The East African. Agence France Presse. 13 March 2020.
- ↑ "Sudan stops visas and flights for eight countries including Egypt over coronavirus: statement" (in en). Reuters. 12 March 2020. https://www.reuters.com/article/us-health-coronavirus-sudan-idUSKBN20Z36I.
- ↑ "Surge in deaths in North Darfur raises fears of disastrous Covid-19 outbreak". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-29. Retrieved 2020-05-29.