Àwọn ìdìmúlẹ̀ jẹ́ àwọn òpó àti ọ̀nà ìṣe ètò àwujọ àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tó úndarí ìwà àkójọpọ̀ àwọn ẹnikọ̀ọ̀kan nínú ibi ìgbépapọ̀ kan. Àwọn ìdìmúlẹ̀ jẹ́ mímọ̀ pọ̀ mọ́ social purpose àti ìdúróṣinṣin, èyí tó kọ́ jáa ìgbésíayé àti èrò ẹnikọ̀ọ̀kan, àti nípa ṣiṣe àti gbígbéró àwọn ilànà-òfin tó úndarí ìwà àjọṣe àwọn ènìyàn.[1]

Israel Silvestre, Collège des Quatre-Nations

Àwọn irú ìdìmúlẹ̀ àtúnṣeÌtọ́kasí àtúnṣe

  1. http://plato.stanford.edu/entries/social-institutions/ Stanford Encyclopaedia: Social Institutions