Ìdajọ lori óju ọjọ

Ìdajọ lori óju ọjọ da lóri ṣiṣè amujutó ipa àyipadà ójù ọjọ ati imujutó awọn ẹ̀tọ èniyan to farapa nitori ìṣẹ̀lẹ naa[1][2][3].

Ìdàṣẹsilẹ lori óju ọjọ to wayè ni Berlin, óṣu September, ọdun 2021
Ìlè ẹjọ to ga ti Netherland ni ọdun 2019
Awọn ólùkopa ninu irin ajijagbàra lori ìdajọ óju ọjọ bèrè fun àyipada ètó

Awọn àtunṣè lori Idàjọ lori òju ọjọ

àtúnṣe
 
Àgbèjọ lori ìdajọ óju ọjọ ni Epo Refinery ti Chevron ni Richmond, California (2009)
 
Ẹgbẹrun lọna mẹwa èniyan fẹhunu han fun ìdajọ óju ọjọ ni Copenhagen (2009)

Awọn ìpènijà idajọ lori ójù ọjọ

àtúnṣe
 
Ilè yii parun latari ìkun ómi ni New Orleans, Louisiana

Nigbati awọn àṣofin, awọn ọjọgbọn ati iwadi fun imọran ko ba sinibẹ, eyi le di atunṣè lori ayipada óju ọjọ ku. Ìdajọ lori óju ọjọ lèjẹ ọna ati dojukọ awọn ilu ti ko ni lo atunṣè lori ayipada óju ọjọ nigba ti wọn o fẹ afẹfẹ sita ni ayè atijọ[4][5].

Awọn Ìtọkasi

àtúnṣe
  1. "Climate Equity or Climate Justice? More than a question of terminology". IUCN. 2021-03-19. Retrieved 2023-09-30. 
  2. Dooley, Kate; Holz, Ceecee; Kartha, Sivan; Klinsky, Sonja; Roberts, J. Timmons; Shue, Henry; Winkler, Harald; Athanasiou, Tom et al. (2021). "Ethical choices behind quantifications of fair contributions under the Paris Agreement". Nature Climate Change (Springer Science and Business Media LLC) 11 (4): 300–305. doi:10.1038/s41558-021-01015-8. ISSN 1758-678X. 
  3. Law, Enforcing Climate Change (2003-08-01). "Climate Justice: enforcing climate change law — Climate Justice Programme". climatelaw.org. Archived from the original on 2011-04-09. Retrieved 2023-09-30. 
  4. Chauhan, Chetan (2021-10-30). "China will take one-third of carbon space by 2030, India 7%, says CSE". Hindustan Times. Retrieved 2023-09-30. 
  5. Mathiesen, Karl (2022-10-19). "Climate talks: Should rich countries pay for damage caused by global warming?". the Guardian. Retrieved 2023-09-30.