Ìdomà
eya orile-ede Naijiria
Èdè Idoma A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílẹ̀ èdè Náígíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ igba méjì ati àádọ́ta ẹgbẹ̀rún.[1] Àwọn aládùgbóò rẹ̀ ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n jẹ agbẹ. Wọ́n si máa ń se àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú.[2][3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Idoma language". DBpedia (in Èdè Jámánì). 1999-02-22. Retrieved 2023-06-14.
- ↑ "Idoma language". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2023-06-14.
- ↑ "Idoma Words, Phrases & Pronunciations". IdomaLand. Retrieved 2023-06-14.