Ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́

Ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ jẹ́ ìfẹ́ tí kò ní gbèdéke, tàbí tí kò ní àní-àní. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ó ní ìtumò tí wón fún ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ gbàgbọ́ pé ó jẹ́ ìfẹ́ tí kò ní gbèdéke tí kò sì lẹ yí padà lábé oun tí ó bá wù kí ó ṣẹlẹ̀.

Ìfẹ́ òbí sí ọmọ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àpẹẹrẹ ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́

Gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ àwọn Ẹ̀lẹ́sìn Krístì gbàgbọ́ pé ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìfẹ́ mẹ́rin tí ó wà; Ìfẹ́ láàrin àwọn ẹbí, Ìfẹ́ láàrin ọ̀rẹ́, ìfẹ́ ìbálòpọ̀, àti ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́.[1]

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. Lewis, C. S. (1960). The Four Loves. Ireland: Harvest Books. ISBN 0-15-632930-1.