Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Akáríayé

Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Oníkíkáríayé (IOC ni ede geesi duro fun International Olympic Committee) je egbe ikojo to budo si Lausanne ni orile-ede Switzerland ti Pierre de Coubertin ati Demetrios Vikelas dasile ni 23 June, odun 1894. Awon omo egbe je awon 205 Igbimo Olympiki ti awon Orile-ede.

International Olympic Committee
Comité international olympique
Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Oníkíkáríayé
Ìdásílẹ̀June 23, 1894
TypeSports federation
IbùjókòóLausanne, Switzerland
Ọmọẹgbẹ́205 National Olympic Commitees
Official languagesEnglish, French
PresidentThomas Bach
Websitehttp://www.olympic.org
Ibujoko IOK ni Lausanne.