Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Akáríayé
(Àtúnjúwe láti Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Káàkiriayé)
Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Oníkíkáríayé (IOC ni ede geesi duro fun International Olympic Committee) je egbe ikojo to budo si Lausanne ni orile-ede Switzerland ti Pierre de Coubertin ati Demetrios Vikelas dasile ni 23 June, odun 1894. Awon omo egbe je awon 205 Igbimo Olympiki ti awon Orile-ede.
International Olympic Committee Comité international olympique Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Oníkíkáríayé | |
---|---|
Ìdásílẹ̀ | June 23, 1894 |
Type | Sports federation |
Ibùjókòó | Lausanne, Switzerland |
Ọmọẹgbẹ́ | 205 National Olympic Commitees |
Official languages | English, French |
President | Thomas Bach |
Website | http://www.olympic.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |