Ìjàmbá
Àyọkà yìí únfẹ́ ìyílédèdà sí Yorùbá. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ ṣàtúnṣe sí ìyílédèdà |
Àdébá jẹ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àìròtẹ́lẹ̀ tí a ò gbáradì fún, ní ọ̀pọ̀ ìgbà, ó máa ń jẹ́ pẹ̀lú àìgbèrò tàbí àìní ìwúlò. Nìgbà gbogbo, ó túmọ̀ sí ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo-gbòò èyítí a lè yàgò fún tií ó bá ṣe pé ohun tí ó fa ìjàmbá náà ti di mímọ́ fún wa tẹ́lẹ̀ tí a sì ti dènà dèé ṣíwájú kí ìṣẹ̀lẹ̀ láabi náà tó ṣẹ̀.
Fún àpẹẹrẹ, Bí igi bá ṣubú lulẹ l'ákókò ìjì, ìṣubú rẹ le máà jẹ́ láti ọwọ́ ènìyàn kankan, ṣùgbọ́n ìrù igi tí ó jẹ́, ìwọ̀n rẹ̀, ìlera rẹ̀, ibi tí ó wà, tàbí àìrí ìtọ́jú lè jẹ́ òkùnfà ìṣubú yìí . Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀rún ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ kìí ṣe nípasẹ̀ àwọn ìjàmbá; síbẹ̀síbẹ̀, àwọn tí ń sọ gẹ̀ẹ́si bẹ̀rẹ̀ lílò ọ̀rọ̀ yìí ní ǹkan bíi ìdajì ogún sẹnturi, latari ìfọwọ́yí ìròyìn láti ọwọ́ àwọn ilé-iṣé mọ́tò ní Amẹ́ríkà.
References
àtúnṣeExternal links
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Ìjàmbá |